BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Etọ awọn obinrin
'Mi ò rí ọkùnrin bá lòpọ̀ fún ọdún kan gbáko lásìkò "lockdown" àmọ́ mo dán ǹkan wò'
18 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Kí ni ìdí tí wọ́n fi ń lọ́ ọmú obìnrin nílẹ Adúláwọ̀?
17 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Èmi àti ọmọ ẹgbẹ́ akọrin wa jọ yó ìfẹ́ ara wa ni - Pásítọ̀ ní òun kò jẹ̀bi ẹ̀sùn ìfipábáni lòpọ̀
16 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Wo bí ilẹẹjọ́ ṣe yí ẹ̀bẹ̀ Baba Ijesha dànù lórí ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀ tí wọ́n fi kàn án
15 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Pásítọ̀ àti ìyàwó rẹ̀ l'Ogun ní Èṣù ló wà nídìí ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀ pẹ́lú ọmọ akọrin ọdún 16 ní ṣọ́ọ̀ṣì- Ọlọ́pàá
13 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Ojú ará bẹ̀rẹ̀ sí ní ta mí lẹ́yìn tí Gbenga Filani fipá bámi lòpọ̀- olóyún ọmọ ọdún19
11 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Itunu Babalola kó tó di olóògbé tí wọ́n ń fi òkú rẹ̀ ránṣẹ́ sílé...
5 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Àwọn ọlọ́pàá ti ń wá okùnrin tó gbé òkú ọ̀rẹ́bìnrin rẹ̀ sínú fííjì lẹ́yìn tó gbẹ̀mí rẹ̀ tán
24 Bélú 2021
Ìjọba Eko fi ọwọ́ ọlà gbá ìyá Jumoke lójú ní ₦1m àti ilé tó hááyà fún - Agbẹjọ́rò
22 Bélú 2021
Mọ̀ nípa àìsàn tó ń mú kí irun pọ̀ lára obìnrin láì ṣe ọkùnrin
21 Bélú 2021
11:19
Fídíò,
Àwọn ọmọ ọkùnrin mẹ́tà ló tì mí mọ́lé tí wọ́n ń bá mi sùn lójoojúmọ́ ní Libya - Ìrírí ìyá àti ọmọ
, Duration 11,19
15 Bélú 2021
Ilé ẹjọ́ gba béèlì àwọn òṣìṣẹ́ ilé ọmọ aláìlóbìí méjì tí wọ́n lo ta ọmọ obìnrin alárùn ọpọlọ
11 Bélú 2021
"Ọmọ kan ṣoṣo tó bí fún mi ni wọ́n gún lọ́dún mẹ̀ta sẹ̀yìn kí wọ́n tó gún òun náà pa báyìí"
10 Bélú 2021
Ajàfẹ́tọ́ obìnrin tó wá sí Nàìjíríà torí àwọn akẹ́kọ̀ọ́bìnrin Chibok tí wọ́n jígbé Malala Yousafzai ṣe ìgbéyàwó
10 Bélú 2021
Mi ò lè sùn, mó ń ronú, mi ò lè ṣe ǹkan torí Lanre - Princess
10 Bélú 2021
Àwọn ọkùnrin wá kọ̀ láti ṣe- Ìdí tí àwọn obìnrin ṣe n tọ́jú ibòjì okú ni abúle kan
7 Bélú 2021
Alùlùgbayì ọmọ Nàìjíríà tó fI Ìlù kojú ìdẹ́yẹsí ní Amẹ́ríkà rèé
7 Bélú 2021
5:13
Fídíò,
Kàyèéfì! Mo ní àrùn jẹjẹrẹ tẹ́lẹ̀ àmọ mo bí ìbejì lẹ́yìn tí nǹkan oṣù ti dúró - Olorì Olugbon
, Duration 5,13
3 Bélú 2021
Obìrin tó ń ta omi inú ọ̀rá subú pẹ̀lú ọmọ lẹ́yìn torí ebi
29 Ọ̀wàrà 2021
Wo ohun tí Yinka Alaseyori sọ nipa Tope Alabi ní àyájọ̀ ọjọ́ ìbí rẹ̀
27 Ọ̀wàrà 2021
Ìfẹ́ ńlá rèé o! Ọmọbabìnrin pàdánù ipò ọlá rẹ̀ láti fẹ́ atàpátadìde ní ọkọ
26 Ọ̀wàrà 2021
Obìnrin mẹ́fà àti ọmọ wẹ́wẹ́ mẹsan sá ní àhámọ́ Boko Haram lẹ́yìn oṣù mẹ́fà
12 Ọ̀wàrà 2021
Wàládè dé! Àwọn obìnrin aṣaralóge wọ gàù ikọ̀ Taliban ní Afghanistan
10 Ọ̀wàrà 2021
5:27
Fídíò,
Láti ìgbà ti mo ti fún ọkọ mi ni ẹ̀bùn ni ìfẹ́ wa ti pọ̀ síi; ẹ̀yin obìnrin, ẹ ni iṣẹ́ lọ́wọ́ láti lè ni òmìnira láti máa ra ẹ̀bùn
, Duration 5,27
7 Ọ̀wàrà 2021
Ìṣájú
Page
16
nínú
30
1
13
14
15
16
17
18
19
30
Tókàn