BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Etọ awọn obinrin
8:01
Fídíò,
Bíbélì kò sọ pé kí Oníwàásù má sọ̀rọ̀ owó, ṣe òkúta ló fẹ́ ná ní- Funke Felix Adejumo
, Duration 8,01
7 Agẹmo 2022
MaryGotFit :obìnrin bí ọkùnrin agbírinsápá ṣàlàyé ìdẹ́yẹsí tó ń kojú nídìí iṣẹ́ tó yàn láàyò
3 Agẹmo 2022
Osinachi Nwachukwu n wọ káà ilẹ̀ sùn lónìí, ètò ìsìnkú ìkẹhìn ti bẹ̀rẹ̀!
25 Òkùdu 2022
3:59
Fídíò,
'Ariwo yéè! Kí léléyìí, kí lo kó yìí, Ọlọ́run jọ̀ọ́ jẹ́ kí èmi náà ní irú ẹ̀ làwọn míì máa ń pa lé mi lórí'
, Duration 3,59
25 Òkùdu 2022
Odindi ọdún 17 ni mo fi wá iṣẹ́ pẹ̀lú ìwé ẹ̀rí "Mass Comm", èrè tí mò ń rí nídìí wíwa Keke Maruwa
24 Òkùdu 2022
Àwọn agbébọn tún gbẹ̀mí àlùfáà ìjọ Àgùdà míì ní Edo
23 Òkùdu 2022
Ìbejì olórin ẹ̀mí Osinachi jẹ́rìí nílé ẹjọ́ níbi ìgbẹ́jọ́ ọkọ rẹ̀, Peter Nwachukwu
22 Òkùdu 2022
“Phone repairer” tó pín àwòrán ìhòhò obìnrin oníbarà rẹ̀ lórí ayélujára rí ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́rìnlá he
22 Òkùdu 2022
Ob̀inrin yìí pa ọkọ rẹ̀ lẹ́yìn tó ko ìwé nípa ‘How to murder your husband’
16 Òkùdu 2022
Ariwo kò yẹ kóo máa gbé Kùránì dání pẹ̀lú iṣẹ́ aṣẹ́wó tí ò ń se ní wọ́n pa kí wọ́n tó dáná sun òkú náà
15 Òkùdu 2022
Káre Efunroye Tinubu! Ògbóǹtagí oníṣòwò, olówò ẹrú àti afọbajẹ
4 Òkùdu 2022
7:29
Fídíò,
'Wọ́n sọ fún ìyà mi kó jù mi nù nígbà tí mò ń fi àyà fà bí ejò àmọ́ mo di àrídunú pẹ̀lú gbígbé "weight"
, Duration 7,29
3 Òkùdu 2022
"A ó pàdé níbi ìdájọ́ lọ́run" ni ọ̀rọ̀ tí obìnrin tó pa ara l'Eko fi sílẹ̀ fún ẹbí rẹ̀ - Ọlọ́pàá sọ ohun tí wọ́n mọ̀
30 Èbibi 2022
Taliban gbé òfin kalẹ̀ lórí àwọn Obìnrin atọ́kùn ètò, bó ojú rẹ tóo bá fẹ́ ka ìròyìn bí bẹ́ẹ̀ kọ́.....
23 Èbibi 2022
"Ogun ló gbé mi lọ sí Central African Republic, àmọ́ ọmọ ni mo gbé bọ̀"
22 Èbibi 2022
Ẹ dákun, ẹ má jẹ̀ẹ́ kí ọkọ mi fi lílù pamí – Ìyàwó rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí ilé ẹjọ́
17 Èbibi 2022
Láí ṣẹ̀ láí rò, wọ́n jó Ṣọ́ọ́ṣì mi pátápátá ní Sokoto, ìrírí mi rèé - Pasitọ ìjọ Celestial
17 Èbibi 2022
Agbẹjọ́rò 34 táa tán nílé ẹjọ́, bí wọ́n ṣe sọ àwọn afurasí tó lọ́wọ́ nínú ikú Deborah Samuel sẹ́wọ̀n rèé
17 Èbibi 2022
Ìdajì ilé mi ni mo tà láti rán ọmọ mi nílé ẹ̀kọ́ àmọ́ wọ́n gbẹ̀mì rẹ̀ láìtọ́jọ́ - Bàbá Deborah Samuel
16 Èbibi 2022
12:04
Fídíò,
Kò sí ááyà Quran kankan tó ní kẹ́ẹ sọ ẹni tó bá bú Anọ́bì Muhammad l'ókò pa, ẹni tó bá mọ̀ọ́ kó múu jáde – Akeugbagold
, Duration 12,04
16 Èbibi 2022
A ò sọ pé ọmọ orílẹ̀ èdè Niger ni àwọn afurasí ta mú ní Sokoto - Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá
16 Èbibi 2022
Ìjọba Sokoto kéde òfin kóníléógbélé lẹ́yìn ìfẹ̀hónúhàn lórí bí ọlọ́pàá mú àwọn tó pa Deborah Samuel
14 Èbibi 2022
"Ọlọ́pàá ní kí n bọra sílẹ láti mọ bóyá obìnrin ní mí torí mo ní irùngbọ̀n"
14 Èbibi 2022
Ọwọ́ tẹ afurasí ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn ní ilé ìtura, wo nǹkan tí ọlọ́pàá ká mọ lọ́wọ́
12 Èbibi 2022
Ìṣájú
Page
13
nínú
30
1
10
11
12
13
14
15
16
30
Tókàn