BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Awujọ
Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ṣàfihàn ojú àwọn afurasí tó se ẹran ara ọlọ́pàá jẹ ní Ibadan
24 Bélú 2020
Makinde ya ₦56.3 bílíọ̀nù sọ́tọ̀ fún ètò ẹ̀kọ́ nínú àbá ètò ìṣúná ọdún 2021
23 Bélú 2020
Wo ohun mẹ́wàá tó yẹ kí o mọ̀ tí o bá fẹ́ lọ fún ìsinmi lẹ́yìn Covid 19
23 Bélú 2020
3:54
Fídíò,
Toríi "Coro", ẹ wo bí ètò ìsìn ìgbéyàwó orí ayélujára Zoom ṣe lọ
, Duration 3,54
13 Bélú 2020
Ilé ẹjọ́ tú ìgbéyàwó ọdún mọ́kànlá ká nítórí pé ìyàwó fí ìbálòpọ̀ dun ọkọ rẹ̀
12 Bélú 2020
''Aláàfin kìí ṣe ọkùnrin tí wàá jẹ lásán, tó sì wá sálọ - Aráàlú fèsì fún Olorì Anu
12 Bélú 2020
Èèyàn 1,076 ni ìjàmbá mọ́tò ti sọ di olóògbé láti oṣù mẹ́ta sẹ́yìn ní Nàìjíríà- FRSC
11 Bélú 2020
Iléẹjọ́ mú ọjọ́ kejìdínlógún, oṣù kọkànlá fún ìgbẹ́jọ́ àwọn tó jí ìbejì Àáfà Akeugbagold ní Ibadan
9 Bélú 2020
3:52
Fídíò,
Nígbà tí mo dàgbà ní mo rí i pé oore ńlá ní Olorun ṣe mi pẹ̀lú aàbọ̀ ara mi- Bose Okeowo
, Duration 3,52
7 Bélú 2020
Ẹkún àti ìbànújẹ́ láwọn mọ̀lẹ́bí fi sìnkú ọmọ méje ní Kumba, Cameroon lónìí
5 Bélú 2020
Wo iye àwọn tí wọ́n ti gbà sí ikọ̀ SWAT báyìí àti òfin ti wọ́n fún wọn
5 Bélú 2020
13:49
Fídíò,
Mọ̀ síi nípa òwò jìbìtì tuntun Crowd 1 tó gbòde kan lásìkò yìí
, Duration 13,49
3 Bélú 2020
Ta ni Wolii Olapade Agoro tó re ibi àgbà ń rè tí ayé ń pariwo rẹ̀ yìí?
2 Bélú 2020
Oluwo ti ìlú Iwó kìí ṣe ẹgbẹ́ Àtaọjà Osogbo - Alaafin ìlú Ọ̀yọ́
2 Bélú 2020
2:08
Fídíò,
Ẹ̀gbọ́n mi tán ìṣòro mi nípasẹ̀ ṣíṣe ẹ̀ya ara àtọwọ́dá fún mi- Ubokobong Sunday
, Duration 2,08
1 Bélú 2020
5:17
Fídíò,
'Àwọn òṣèré aparí pọ̀ táa ti ṣe iṣẹ́ abẹ irun fún tẹ́ẹ ma rò pé wọ́n gẹ "low cut" ni'
, Duration 5,17
31 Ọ̀wàrà 2020
Mo pinu láti dá Iphone tì mo mú padà kí ọlọ́pàá tó mú mi
31 Ọ̀wàrà 2020
Ìjọba Eko kọ orúkọ sí "Palliatives" tiwọn lára o, mo ní ẹrù tèmi f'ọjọ́ ìbí mi tí wọ́n jí - Họ́nọ́rébù Agunbiade
30 Ọ̀wàrà 2020
Báyìí ni 50 Kobo ṣe dá ìfẹ̀hónú "Ali Must go" sílẹ̀ tó mú ọ̀pọ̀ ẹ̀mí akẹ́kọ̀ọ́ lọ
29 Ọ̀wàrà 2020
Àwòrán nǹkan aláràmbarà oríṣiríṣi táwọn jàǹdùkú jí gbé lẹ̀yìn ìwọ́de EndSARS
27 Ọ̀wàrà 2020
Buhari kò láànú ọmọ Nàìjíríà lójú - Aisha Yesufu
23 Ọ̀wàrà 2020
Ìrẹ̀wẹ̀sì ń bá wa torí ìdánwò NECO tẹ ń ṣún síwájú lọ́pọ̀ ìgbà - Akẹ́kọ̀ọ́, ọ̀gá iléèwé
19 Ọ̀wàrà 2020
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ 181 pẹ̀lú Olùkọ́ lùgbàdì Covid 19 níléèwé aláàdáni kan nípinlẹ̀ Eko
17 Ọ̀wàrà 2020
Ọkọ̀ akẹ́rù tí ìjánu rẹ̀ já ló kọlù ọkọ̀ agbépo tó fa ìjàmbá iná ní Otedola- LASEMA
17 Ọ̀wàrà 2020
Ìṣájú
Page
29
nínú
40
1
26
27
28
29
30
31
32
40
Tókàn