You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n
Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.
Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́
Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo
Ọ̀nà tí a lè fi san oore fún àwọn tó fi ẹ̀mí wọn lélẹ̀ fún ìjọba àwarawa ni láti lé APC kúrò lórí oyè - Atiku
A kò ní ṣe ayẹyẹ ọdún June 12 nítorí ìkọlù tó wáyé nílùú Owo - Akeredolu
"A ó pàdé níbi ìdájọ́ lọ́run" ni ọ̀rọ̀ tí obìnrin tó pa ara l'Eko fi sílẹ̀ fún ẹbí rẹ̀ - Ọlọ́pàá sọ ohun tí wọ́n mọ̀
Shina Peller àti Teslim Folarin tahùn síra wọn lórí ẹ̀sùn ìpànìyàn, wàhálà ṣẹlẹ̀ n'ídìbò abẹ́nú Oyo
Kunle Adeyanju tí ó gun alùpùpù láti London ti balẹ̀ bìbà sí Nàìjíríà
Èèyàn 31 kú lẹ́yìn tí wọ́n tẹ wọ́n pa níbi tí ilé ìjọsìn ti ń pín oúnjẹ ọ̀fẹ́ ní Port Harcourt
"Ogun ló gbé mi lọ sí Central African Republic, àmọ́ ọmọ ni mo gbé bọ̀"
Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá nawọ́ gán afurasí mẹ́fà lórí ikú "Sound Engineer"
A kò fẹ́ kí Kumuyi wá ṣe ìsọjí ìta gbangba nílùú Abia – IPOB
Lẹ́yìn wákàtí díẹ̀ tí wọ́n sin òkú n'Ibadan, àwọn afurasí olóogùn owó gé orí rẹ̀ lọ
A kò fi ti gbèdéke June 1 ṣe, a ti fòfin de ọ̀kadà, kèké ní Eko
"₦20,000 ló kàn mí lẹ́yìn tí a ja Iléeṣẹ́ rédíò Yinka Ayefele lólè ní Ibadan"
Alága ẹgbẹ́ ADP l’Ekiti ní òun kò ṣe ẹgbẹ́ mọ́ ṣáájú ìbò gómìnà l'óṣù Kẹfà
Ilé ẹjọ́ wọ́gilé àfikún ẹjọ́ tí ìjọba àpapọ̀ pè tako Nnamdi Kanu
Ẹ dákun, ẹ má jẹ̀ẹ́ kí ọkọ mi fi lílù pamí – Ìyàwó rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí ilé ẹjọ́
Ìdajì ilé mi ni mo tà láti rán ọmọ mi nílé ẹ̀kọ́ àmọ́ wọ́n gbẹ̀mì rẹ̀ láìtọ́jọ́ - Bàbá Deborah Samuel
Osun 2022: Kò sí ìjà mọ́, Adeleke àti Babayemi ṣetán láti jọ ṣiṣẹ́ papọ̀
Kò sí ááyà Quran kankan tó ní kẹ́ẹ sọ ẹni tó bá bú Anọ́bì Muhammad l'ókò pa, ẹni tó bá mọ̀ọ́ kó múu jáde – Akeugbagold
A ò sọ pé ọmọ orílẹ̀ èdè Niger ni àwọn afurasí ta mú ní Sokoto - Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá