You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.

Take me to the main website

Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n

Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.

Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́

Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo

  1. Ẹ̀yin tẹ́ẹ fẹ́ máa ṣe "prank" pa owó bíi tèmí, ẹ má dán an wòo torí adúrú ìyà tó ń jẹ mi yìí - Trinity guy

  2. Eze Ndigbo tó ní òun yóò fìwé pe IPOB wá sí Eko fojú balé ẹjọ́ lórí ẹ̀sùn ìgbésùmọ̀mí

  3. Ààrẹ Buhari fi ọ̀ṣẹ̀ kan kún ìrìnàjò rẹ̀ sí ìlú London láti ṣe àyẹ̀wò eyín

  4. Afurasí 'ọmọ yahoo' fi ọkọ̀ pa akẹ́kọ̀ọ́ tó n ṣe WAEC lọ́wọ́ nílùú Akure

  5. ‘Mo ti dáríjin ìbátan mi tó da ásíìdì sí mi lára’

  6. Ìjàmbá iná lọ́jà Alaba l'Eko, ará ọjà àti iléeṣẹ́ panápaná tako ara wọn lórí aìráye pa iná náà

  7. Wo ọ̀nà láti gbógun ti àìsàn Ibà lásìkò yìí

  8. Ìtàn Ọba Yorùbá tí wọ́n yẹgi fún torí ó jí ọmọ gbé ṣe ètùtù

  9. Ìdí tí mi ò fi kí ń ṣí ìhòhò ara mi sílẹ̀ tí mo sì yàn láti máà múra bí ọkùnrin ni pé ... - Teni the Entertainer

  10. Wo ọ̀nà àbáyọ márùn ún fún obìnrin àti ọkùnrin tó bá lẹ̀pọ̀ lásìkò ìbálòpọ̀

  11. Èmi àti ọkọ mi ń fi iṣẹ́ àgbẹ̀ ṣoríire báyìí l'Ámẹ́ríkà àmọ́, ìmọ̀ràn wa fún ẹ̀yin ọ̀dọ́ Nàìjíríà ni pé ... - Temitope àti Olaniyi Balogun

  12. 'Ta ni yóò tọ́jú mi lẹ́yìn ikú Oreoluwa' - ìyáìyá àgùnbánirọ̀ tó kú sínú ìjàmbá ọkọ̀ Eko figbe bọnu

  13. Ìye ìgbà ìbálòpọ̀ kọ́ ló ń jẹ́ kí abẹ́ obìnrin fẹ̀, ohun tí ọkùnrin lè fí mú obìnrin gbádùn ìbálòpọ̀ rèé - Yinka TNT

  14. Wo àwọn èsì ìbò tó gbé Bola Tinubu wọlé bíi ààrẹ Nàíjíríà

  15. Ṣé lóòtọ́ ní INEC mọ̀ọ́mọ̀ yọ àsíà labour Party kúrò lórí ìwé ìdìbò?

  16. Àwọn olórí orílè-èdè ilẹ̀ Áfíríkà mẹ́fà tó rọ́pò òbí wọn gẹ́gẹ́ bí ààrẹ.

  17. Mọ̀ síi nípa ewu tó rọ̀ mọ́ níní ìbálòpọ̀ lásìkò ìlóyún lórí ètò Sé lóòtọ́ ní BBC

  18. Bola Are kẹnu bọ ọ̀rọ̀ lórí àwọn èdè orin àti ìhùwàsí àwọn Olórin ẹ̀mí lóde òní

  19. ̀̀́Wo ǹkan mẹfà tí o kò mọ nípa ẹyà Coronavirus tuntun

  20. COVID-19, Ẹ fọkàn balẹ̀ ìjọba Nàìjíríà kò ni jẹ́ kí Coronavirus tàn kálẹ́ rára- Minisita ìlera