Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Idajọ mi rèé, ẹ lọ yẹgi fun wọn
Yẹgi fawọn wo, nigba wo lo dadajọ?
Emi kọ o, Adajọ Haleema Salman ile ẹjọ giga niluu Ilorin lo ti dajọ iku
fáwọn ọ̀daràn márùn ún tó ṣọṣẹ́ níbi iṣẹlẹ ìdigunjalè báńkì tó wáyé nílùú Offa lọdun mẹfa sẹyin nibi ti Ọpọ ẹmi ti ṣofo
Kan si oju opo BBC.com/Yoruba ẹkunrẹrẹ
E mi la o ni yọ si, ba a se fẹ ko ri bẹ naa lo ri
Ewo la tun rigbọ o, ṣoo jẹ tẹtẹ ni?
Rara o, Ijọba apapọ ma lo ti ṣalekun owo ajẹmọmu awọn agunbanirọ to n ṣe iruulu lati N33,000 to wa tẹlẹ si N77,000
Ẹkunrẹrẹ iroyin naa wa lori ikannin BBC Yoruba
Ẹ ye tabuku iṣẹṣe ninu fiimu tẹ n gbe sita, ẹ jawọ nbẹ!
Awọn oniṣẹṣe lo ke gbajare bẹẹ nibi ipade ti wọn ṣe pẹlu awọn oṣere tiata n’Ibadan
Awọn oṣere naa da a pada pe ohun to n ṣẹlẹ lawujọ lawọn n gbe sita ninu ere
Kan soju opo BBC.COM/Yoruba fun ẹkunrẹrẹ


























