You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ki lo ṣẹlẹ gan an ti tomato fi gbowo lori bayii?
O gbẹnutan o, owo kekere o to s'ebọ mọ, amọ, BBC ti ṣewadii lori idi abajọ
ẹnh ẹnh. Ki wa ni abọ iwadii ọhun?
Ti o ba fẹẹ mọ, tete lọ sori ikanni BBC Yoruba fun ẹkunrẹrẹ
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Pekele pekele arugbọ jẹ gbese tani o san an?
Ki lo de ta lo jẹ gbese e?
Ajọ EFCC ti fidi rẹ mulẹ pe owo to to Trilliọnu kan ati biliọnu lọna ọọdunrun naira lo wọgbo sibi eto idokowo ori ayelujara CBEX to lulẹ
Eṣi o! Bawo lawọn eeyan ṣe fẹẹ rowo wọn gba bayii?
EFCC ni awọn yoo siṣẹ pọ pẹlu ajọ ọtẹlẹmuyẹ Interpol lati fi oju awọn asebi han
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Njẹ o ti ẹ mo bi Portable ṣe pada kuro lọgba ẹwon n'Ilorin?
Rara o! Bawo lo ṣe ṣee gan lẹyin ti alaga ẹgbẹ awọn olorin PMAN ni Kwara kọ lati ṣe oniduro fun un?
Woo, maa laagun jinna, alaye wa lori ikanni BBC Yoruba