Kò ṣe é mà gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é mà gbọ̀ ọ́
Published
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Ẹgbẹ oṣiṣẹ NLC ti kede pe awọn yoo ṣe iwọde kaakiri Naijiria

tijọba ba tẹsiwaju pẹlu erongba rẹ lati ṣe afikun tariifu owo ina mii

NLC ni kii ṣe asiko yii ti ọwọngogo nnkan gbode ni Naijiria lo yẹ ki ijọba maa gbero lati ṣafikun owo ina.

====================================

Awuyewuye lori aawẹ Ramadan

Bi ti bawo, ki lo fẹ fa awuyewuye lori aawẹ?

Bẹẹ la a bi ni o, ọpọ eeyan lo ti koro oju si bijọba ipinlẹ mẹrin to n samulo ofin Sharia, se gbe ilẹkun ile ẹkọ wọn ati ti aladani ti pa fun osu kan gbako tori aawẹ to n lọ lọwọ.

Iyẹn ma gbẹnutan an, awọn ipinlẹ wo gan na ni?

Idahun s'iberee rẹ wa loju oju opo BBC Yoruba

'''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Ọmọ akin o gbọdọ ṣojo, mo fi ara mi silẹ fawọn ajinigbe nigba ti wọn fẹ mu iyawo mi lọ

Olabiyisi Mobolaji Charles tawọn Amotekun doola lọwọ awọn Amotekun lo sọ bẹẹ

Olabiyisi ni miliọnu mẹwaa naira lawọn ajinigbe lawọn o gba kawọn ẹsọ Amotekun to de

Ẹkunrẹrẹ wa lori ikanni BBC.Com/Yoruba