Ẹ má sá fún ọmọ ẹlẹ́gbẹ́, ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ wọn yóò là – Ifatolani Ayoka, Olórí emèrè ṣàlàyé

Àkọlé fídíò, Ẹ má sá fún ọmọ ẹlẹ́gbẹ́, ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ wọn yóò là – Ifatolani Ayoka, Olórí emèrè ṣàlàyé
Ẹ má sá fún ọmọ ẹlẹ́gbẹ́, ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ wọn yóò là – Ifatolani Ayoka, Olórí emèrè ṣàlàyé
Published

Ọpọ eeyan lo maa n fọnrere awọn ọmọ ẹlẹgbẹ ti ọpọ tun mọ si emere gẹgẹbi akanda ati aṣayan laarin awọn iṣẹda Eledumare.

Ko si ọpọlọpọ obi to fẹ bi emere ọmọ ni ilẹ Yoruba.

Ifatomi Ayọka ti ọpọ n pe ni olori Emere ba BBC News Yoruba sọrọ lori otitọ to rọ mọ awọn Emere ati bo ṣe jẹ ninu iṣẹdalẹ Yoruba.