You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Kò ṣe é mà gbọ̀ ọ́
Njẹ o ti gbọ?
Pe ki ni?
Wi pe ijọba ti gbẹsẹ le akaunti ikowosi adari ẹgbẹ Ipob Simon Ekpa atawọn mẹrindinlogun mii
Lori ẹsun pe wọn n sẹ onigbọwọ fun igbesunmọmi ni Naijiria
Awọn wo wa lawọn merindinlogun yooku?
Kan soju opo BBC Yoruba ti o ba fẹ mọ
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Njẹ o mọ pe ipo kẹfa ni Naijiria wa ninu awọn orilẹede ti igbesunmọmi ti gbilẹ ju lagbaaye?
Bun mi gbọ o.
Ajọ to n ṣe odiwọn iwa igbesunmọmi ati aibalẹ ọkan lagbaaye lo fidi ọrọ yii mulẹ
Ajọ naa ṣalaye pe Naijiria ti sun kuro ni ipo kẹjọ to wa lọdun 2023 ati 2024
ẹkunrẹrẹ wa lori ikanni BBC Yoruba
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Iku p'Abiri, Abiri lọ, iku p'Abiri, Abiri rọrun
Ta lo tun ku?
Agba oselu Dokita Doyin Okupe ti lo dagbere faye
Oni ọjọ Ẹti ọjọ Keje osu Kẹta ọdun yii ni Okupe jade laye lẹni ọdun mejilelaadọrin
K'Eledua dẹni fẹni're to lọ