BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ilera awọn obinrin
Ẹ̀ṣọ́ ìyàwó Gómìnà Ekiti Bisi Fayemi bọ́ sọ́wọ́ ọlọ́pàá lórí ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀ l'Abuja
14 Agẹmo 2021
Bobrisky fi àwòrán tuntun léde lẹ́yìn tó parí iṣẹ́ abẹ ìdí tó ṣe
10 Agẹmo 2021
Wo ohun tó yẹ kí o ṣe sí ojú abẹ́ rẹ, ''vagina'' lẹ́yìn ìbálòpọ̀
4 Agẹmo 2021
Jẹ́jẹ́ ni Iyabo Ojo jókòó, èmi ni mo pè é sí ọ̀rọ̀ Baba Ijesha - Lola Alao
1 Agẹmo 2021
Oríire dé! Aláànú kan fún Kemisola ní ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ dé fásitì
28 Òkùdu 2021
Ẹ̀bùn owó, oúnjẹ, aṣọ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ní ìkókó mú wọlè fún ẹbí Kemisola Ogunniyi ní Ondo
24 Òkùdu 2021
2:52
Fídíò,
Wo ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ tó ń gba àwọn obìnrin abúlé Bardo ní Nàìjíríà là!
, Duration 2,52
20 Òkùdu 2021
Nkan n bẹ! Páṣítọ̀ lu ìyàwó rẹ̀ pa torí pé ó ń yan àlè
17 Òkùdu 2021
Wọ́n gbé Bobrisky dìgbà-dìgbà padà sílé ìwòsàn lẹ́yìn iṣẹ́ abẹ ìdí
14 Òkùdu 2021
Ọká fóó! Oníṣègùn tó gba 250M owó ẹbọ lọ́wọ́ aláìsàn kó sọ́wọ́ EFCC
14 Òkùdu 2021
Wo ohun tí Dele Momodu sọ nípa TB Joshua lẹ́yìn ikú rẹ̀
13 Òkùdu 2021
Ìrora iṣẹ́ abẹ ìdí tí mo ṣe pọ̀jù, mò ń kú lọ, mo fẹ́ padà sí bí mo ṣe wà tẹ́lẹ̀ - Bobrisky
10 Òkùdu 2021
Wo ilúbìnrin tí wọn ti ń ní ìbálòpọ̀, bímọ̀ láì ní ọkọ
10 Òkùdu 2021
Kàyééfì! Ìyàwó bímọ mẹ́wàá lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo, ọkọ kò níṣẹ́ lọ́wọ́
9 Òkùdu 2021
1:56
Fídíò,
Ṣé o le fi ọṣẹ tí wọ́n fi omi ara ìgbín ṣe fọ ojú?
, Duration 1,56
6 Òkùdu 2021
Mọ̀ si i nípa ìtàn eégún Gelede àti pàtàkì eégún náà sí àwọn obìnrin nílẹ̀ Yoruba
5 Òkùdu 2021
Ṣé lóòtọ́ ni wọ́n fipá bá akẹ́kọ̀ọ́ UNILORIN lòpọ̀ títí tí ẹ̀mí fi bọ́ lára rẹ̀?
3 Òkùdu 2021
Ṣé o mọ̀ pé o leè rí omira abẹ́ obìnrin míì rà tàbi yọ̀ǹda tìrẹ fún lílò?
26 Èbibi 2021
4:27
Fídíò,
Kéèyàn fẹ́ pa ẹ̀fọn tàbí fẹ́ lé eṣinṣin lẹ́sẹ̀ kọ́wọ́ rẹ̀ má tó ó tàbí kó má lè dá dìde - Fatimah Aderounmu
, Duration 4,27
26 Èbibi 2021
Ojú mi rí màbo nígbà tí mo bímọ àkọ́bí, ẹ̀ṣẹ̀ ni ká bímọ láì rí owó tọ́jú rẹ̀ - Lizzy Anjorin
16 Èbibi 2021
Ṣé lóòtọ́ ni Iyabo Ojo ti bẹ Yomi Fabiyi lórí ọ̀rọ̀ Baba Ijesha tó wà ní Panti?
14 Èbibi 2021
Ṣé ǹkan oṣù rẹ ń dà hìì hìì lẹ́yìn tóó gba abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19? Ẹ gbọ́ tuntun lẹ́nu àwọn Dókítà
14 Èbibi 2021
Ṣé lóòtọ́ọ́ ni akẹ́kọ̀ọ́bìnrin fásítì Akungba l'Ondo gbẹ̀mí ara rẹ̀?
13 Èbibi 2021
Ọkùnrin kan bí ẹgbẹẹgbẹ̀rún ni mi, àmọ́ o le darapọ̀ mọ́ ìwọ́de fún Baba Ijẹsha tí o ba tako ìfìyàjẹni
12 Èbibi 2021
Ìṣájú
Page
23
nínú
34
1
20
21
22
23
24
25
26
34
Tókàn