BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ipinlẹ Kwara
Ọ̀pọ̀ ajínigbé ya bo abúlé Alálùbọ́ṣà ní Kwara, ẹ̀mí bọ́, ọ̀pọ̀ farapa
28 Owewe 2023
Ilé ẹjọ́ fún Tani Olohun ní béèlì, àmọ́...
25 Owewe 2023
Àlàyé rèé lórí bí ilé ẹjọ́ ṣe fún Oluwo Nla Tede ní béèlì tó sì sún ìgbẹ́jọ́ Tani Olohun síwíajú
20 Owewe 2023
Ohun tó wáyé níléẹjọ́ rèé lórí ìgbẹ́jọ́ Tani Olohun
11 Owewe 2023
3:58
Fídíò,
Iṣẹ́ dókítà ló wù mí àmọ́ mo di Elékuru láti ran òbí mi lọ́wọ́ – Kehinde Elekuru
, Duration 3,58
8 Owewe 2023
7:29
Fídíò,
“Mo ní ìpèníjà ojú àmọ́ àlàyé rèé lórí bí mo ṣe tọ́ ọmọ mi méjì táwọn náà kò ríran”
, Duration 7,29
6 Owewe 2023
Iléẹjọ́ sún ìgbẹ́jọ́ Tani Olorun síwájú sí ọjọ́ kọkànlá oṣù yìí; Ohun tó ṣẹlẹ̀ rèé
4 Owewe 2023
Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá sàfihàn Alfa tó dúnkokò mọ́ àwọn Oníṣẹ̀ṣe nílùú Ilorin
31 Ògún 2023
Ilé ẹjó fún Ìyá Àbẹ̀bí Olórìsà Osun ní béélì
29 Ògún 2023
Ọlọ́pàá Ilorin bẹ̀rẹ̀ sí ní wá Ọkùnrin tó pe ara rẹ̀ ní Alfa tó ń dúnkokò mọ́ oníṣòwò kan
29 Ògún 2023
Ẹbí ‘Tani Ọlọhun’ rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí àwọn Shehu àti àgbàgbà ẹ̀sìn ní Ilorin láti dáríjin èèkàn Oníṣẹ̀ṣe náà
24 Ògún 2023
Tani ‘Tani Ọlọhun’tó ń dá họ́wùhọ́wù sílẹ̀ fún àwọn Alfaa ìlú Ilorin?
22 Ògún 2023
Ṣé òótọ́ ni pé ayédèrú ìwé ẹjọ́ ni wọ́n fi rán ‘Tani Ọlọ́hun’ lọ s’áhámọ́ fún ẹ̀sùn bíba àwọn Alfa Ilorin lórúkọjẹ́
21 Ògún 2023
Àwọn agbófinró dúró wámúwámú lódò Yemoja n'llọrin, ọdún Ìṣẹ̀ṣe kò wáyé níbẹ̀
20 Ògún 2023
Àrá sán pa ọkùnrin méjì ní Kwara
19 Ògún 2023
Tani Olohun dèrò àhámọ́ ọjọ́ 50 fún bíba Alfa lórúkọ jẹ́ ní Ilọrin
17 Ògún 2023
Ìgbìmọ̀ IFÁ àgbáyé wọ́gilé Ọdún Ìṣẹ̀ṣe nílùú Ilorin
17 Ògún 2023
Àlejò ń fẹ́ lé Onílé jáde lọ̀rọ̀ àwọn Alfa tó ń gbógun tí oníṣẹ̀ṣe nílùú Ilorin- Ifayemi Elebubon
16 Ògún 2023
Ààrẹ Ọ̀nàkakaǹfò gbanájẹ, Ó ní kí ìjọba Kwara ó kìlọ̀ fáwọn alákatakítí ẹ̀sìn Islam tó fẹ́ d’ógun ẹ̀sìn sílẹ̀ ní Ilorin
14 Ògún 2023
Ìyá Olórìṣà dèrò àtìmọ́lé ní Ilorin lẹ́yìn tó fi ẹ̀sùn kan Alfa Okutagidi pé òrìṣà òhun ló gbẹ̀bí ìyàwó rẹ̀
4 Ògún 2023
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́ta rí ẹ̀wọ̀n he ní Ilorin fẹ́sùn ìfipábánilòpọ̀
1 Ògún 2023
Àwon Mùsùlùmí àtàwon onísẹ̀ṣe tọwọ́ bọ̀wé àdéhùn àlááfíà nílùú Ilorin, wọ́n ní kò sí ìjà ẹ̀sìn mọ́
27 Agẹmo 2023
Ṣé lóòótọ́ ni pé àrá sán pa àwọn ajínigbé ní Kwara? Àbọ̀ ìwádìí rèé
16 Agẹmo 2023
9:30
Fídíò,
Mo ti ṣe Bíríkìlà, Apọnmita àti òṣìṣẹ́ ilé iṣẹ́ búrẹ̀dí rí kí n lè rówó ra 'Boot'- Taiwo Awoniyi
, Duration 9,30
3 Agẹmo 2023
Ìṣájú
Page
13
nínú
21
1
10
11
12
13
14
15
16
21
Tókàn