BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ere ori Itage
Ọ̀rọ̀ tí Kemi Afolabi sọ síta lẹ́yìn táwọn kan ráńṣẹ́ síi torí ìtọ́jú àìsàn Lupus tó ní
25 Ẹrẹ̀nà 2022
6:18
Fídíò,
Samuel Ajirebi ọmọ ọdún mẹ́rin àtijọ́ rèé, ó bojú wo fíìmù rẹ̀ ní kékére, máàkì tó fún ara rẹ̀ rèé
, Duration 6,18
23 Ẹrẹ̀nà 2022
Báwo ní àláfíà ara Iyabo Oko, ipò wo ní ìlera rẹ̀ wà?
18 Ẹrẹ̀nà 2022
Ẹ gbà mi o, àwọn oníjìbìtì ayélujára ti ń bèèrè ìrànwọ́ lórúkọ́ mi - Kemi Afolabi lọgun
15 Ẹrẹ̀nà 2022
Ẹsẹ̀ mi yẹ̀ gẹ̀rẹ̀, mo la orí mọ́ táísì, mo sì fẹ́ ẹ̀ pàdánù ọpọlọ nígbà tà ń ya fíìmù - Mide Martins
15 Ẹrẹ̀nà 2022
Wo àwọn òṣèré tíátà tó ti fún Kemi Afolabi lẹ́bùn àtàwọn tó ń kíi lẹ́yìn tó kéde àìsàn rẹ̀
14 Ẹrẹ̀nà 2022
Wo àwọn nǹkan tó le fa lupus - àìsàn tó ń bá Kemi Afolabi fínra
12 Ẹrẹ̀nà 2022
Díẹ̀ lára àwọn òṣèré Nollywood ti wọ́n ti ṣe ìgbéyàwó lẹ́ẹ̀kejì
12 Ẹrẹ̀nà 2022
Dókítà ní ọdún márùn-ún ló kù fún mi láyé, mo sì ti lò lára rẹ̀ - Òṣèré Kemi Afolabi
11 Ẹrẹ̀nà 2022
4:45
Fídíò,
Ẹ̀ ó bẹ̀ mi kúrò láyé ni, mi ò lè kú - Fadeyi Oloro
, Duration 4,45
11 Ẹrẹ̀nà 2022
5:11
Fídíò,
Ẹ wo fíìmù orí ìtàgé eré Mọrèmi, bó ṣe gba Ile-Ifẹe là lọ́wọ́ ìparun
, Duration 5,11
8 Ẹrẹ̀nà 2022
Wo ohun táwọn èèyàn ń sọ sí Mercy Aigbe torí àṣírí tí ìyàwó àkọ́fẹ́ Adekaz tú síta
6 Ẹrẹ̀nà 2022
Gbajúmọ̀ òṣèré tíátà míì ti jáde láyé
1 Ẹrẹ̀nà 2022
Kí ló dé tí Esabod àti Lizzy Anjorin fi ń ṣépè fúnra wọn?
28 Èrèlè 2022
2:57
Fídíò,
Iṣẹ́ tí Ọlọ́run kọ mọ́ mi ni mò ń ṣe -Ṣọla Ṣobọwale
, Duration 2,57
26 Èrèlè 2022
Ìjà d'ópin, ogun ti tán! Ẹ wo bí Mide Martins àtí Olamide àbúrò rẹ̀ ti ń ṣàjọyọ̀ oríire
23 Èrèlè 2022
Ọ̀pọ̀ òṣèré gbarata bí Mama Rainbow ṣe bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kún àsun-ùn-dákẹ́
21 Èrèlè 2022
Mo nífẹ̀ẹ́ ìyàwó mi jú ìyá àtàwọn ọmọ mi lọ - Kolawole Ajeyemi
20 Èrèlè 2022
Kìí ṣe ẹ̀bi àwa òṣèré tíátà pé àwọn ọ̀dọ̀ ń kánjú wá owó - Mr Latin
19 Èrèlè 2022
Ìdí tí mo fi ní ọ́jọ́ ikú ni ọ̀la ọjọ́ 'Valentine' fún àwọn kan- Mike Bamiloye
13 Èrèlè 2022
Ọ̀pọ̀ àgbà òṣèré tíátà péjú sí Ede láti sin Tafa Oloyede déle ìkẹyìn
12 Èrèlè 2022
Iṣẹ́ So-bàtà ní bàbá mi fẹ́ kí ń kọ́ ní Agbeni, kí ń to gba oko eré tíátà lọ - Iya Ibadan Sneh
12 Èrèlè 2022
5:34
Fídíò,
Wọ́n fún mi ní ‘Biscuit’ jẹ ní òde àṣé Igbó ni, inú gbọ̀ngàn ayẹyẹ wá dàbí ebè lójú mi – Olaiya Igwe
, Duration 5,34
12 Èrèlè 2022
Àwọn tó ní mi ò lè bímọ lárùn ọpọlọ, ó nídìí tí mo fi ṣẹ̀ṣẹ̀ bímọ - Yomi Fabiyi
11 Èrèlè 2022
Ìṣájú
Page
15
nínú
31
1
12
13
14
15
16
17
18
31
Tókàn