BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Oniruuru Ẹya ati ajọsepọ wọn
"Awọn ọ̀dọ́ ní Owo lù àwa Hausa, ba ọ̀pọ̀ ọjà wa jẹ́ torí ìkọlù Agbébọn"
11 Òkùdu 2022
6:50
Fídíò,
Babalawo, Ọ̀pẹ̀lẹ̀ ni wọ́n fi ń yan Ọba fún wa, kí ló dé tẹ́ẹ fẹ́ wo owó yan Soun fún wa? - Ọmọ ìdílé òyè l'Ogbomoso
, Duration 6,50
3 Èbibi 2022
'Ó dá mi lójú pé kò ní sí ìdìbò sípò gómìnà ní Osun, Ekiti láíláí ní ọdun 2022!'
20 Ìgbé 2022
Irọ́ tó jìnà sí òótọ́ ni gbogbo ẹ̀sùn rẹ Oluwo - Ohanaeze Ndigbo fèsì
20 Ìgbé 2022
Mò ń bọ̀ nílé láìpẹ́, ìjọba yóò sanwó tó jẹ mí - Sunday Igboho
10 Ìgbé 2022
3:59
Fídíò,
'Mo kọ́kọ́ máa ń ro Amala mi fáwọn ọ̀rẹ́ wa lọ́fẹ̀ẹ́ l'Amẹ́ríkà kí ojú mi tó ṣí tó wá ń já owó gidi fún mi báyìí'
, Duration 3,59
9 Ìgbé 2022
Taa ni Firdauz Abdullahi, ọmọbabìnrin Kano, olòrì tuntun tó ń wọ Ààfin Oluwo lónìí?
20 Ẹrẹ̀nà 2022
Àwọn ọmọ Naijiria tó wà ní Ukraine ké gbàjarè lórí ìdẹ́yẹsí tí wọ́n ń kojú lẹ́nu ibodè EU
28 Èrèlè 2022
Kọmísánnà ọlọ́pàá ní London kọ̀wé fi ipò sílẹ̀ torí ìkéde a kò nígbẹkẹ̀lé nínú rẹ mọ́
12 Èrèlè 2022
Àwọn agbébọn pa ọgọ́ta èèyàn ní ibùdó ìfiniwọ̀ ní DR Congo
3 Èrèlè 2022
Ìyàwó Ẹlẹ́ṣìn ìlú Wukari yarí pé láyé òun ò lè gbà kí ọkọ́ òun wọ igbó mọ́ fún ìsìnkú Ọba
21 Sẹ́rẹ́ 2022
O.Y.O ni Tinubu wa o, a kò ní ṣ'àtìlẹ̀yìn fún un ní 2023 àyàfi ... - Afenifere, Ilana Omo Oodua
13 Sẹ́rẹ́ 2022
Wo àwọn èèkàn mẹ́rin tí Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ pàdánù láàárín oṣù kan
13 Sẹ́rẹ́ 2022
Oluwo gbóríyìn fún Awujale, Akarigbo fún àyípadà òfin lórí àṣà àtijọ́ fún yíyàn Ọba, ṣíṣe ìsìnkú Ọba
12 Sẹ́rẹ́ 2022
11:26
Fídíò,
Ṣé o mọ̀ ipò tí ìlú Owo l'Ondo ní ní Ààfin Ile Ife? Ẹ kálọ sí ìlú mi
, Duration 11,26
31 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
8:32
Fídíò,
Gbogbo àwọn tó ń gbé oúnjẹ́ wá fún mi ni mò ń fi iṣẹ́ búrukú rán sí Ọ̀gá Ọlọ́pàá, ìgbà tí mo ríi pé kò ràn wọ́n...- Ifasooto Dada
, Duration 8,32
28 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Kà nípa ìbẹ̀rẹ̀ ìyàwó Ooni Ife, Olórí Silekunola Moronke Náómì, Wòlíì tó di Ayaba Ile Ife
27 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Ọ̀kùnrin to tú àṣírí ohùn Olóyè Sunday Igboho lórí fóònù ti bọ́ lọ́gbà ẹ̀wọ̀n Cotonou
17 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Naijiria yóò dojúrú tí Buhari bá tú Nnamdi Kanu sílẹ̀ - Ẹgbẹ́ àpapọ̀ l‘Ókè Ọya
23 Bélú 2021
Àwọn alamí ìjọba kan ti wà láàrín àwa ajìjàgbara Yoruba Nation tó ń bínú pé Sunday Igboho ti ga ju àwọn lọ - Akintoye
19 Bélú 2021
2:23
Fídíò,
Oluwo dá èsì ńlá padà fún àwọn olórìṣà tó ní kò tọ́ síi kó ní Ọba Yorùbá kìí ṣe ìgbákejì Òrìṣà
, Duration 2,23
12 Bélú 2021
Alùlùgbayì ọmọ Nàìjíríà tó fI Ìlù kojú ìdẹ́yẹsí ní Amẹ́ríkà rèé
7 Bélú 2021
Àwàdà kẹrí-kẹrì ni ẹ̀sùn ìgbésùnmọ̀mí tí Malami fi kan Sunday Igboho - Ilana omo Oodua
23 Ọ̀wàrà 2021
Ìdí tí Ooni Ogunwusi fi gbé ọmọ rẹ̀ obìnrin tó ṣe ọjọ́ ìbí 28 sáyé àti bó ṣe tọ́ ọ dàgbà
19 Ọ̀wàrà 2021
Ìṣájú
Page
2
nínú
5
1
2
3
4
5
Tókàn