BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Ojú ewé to wà yìí,
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ojú ewé to wà yìí,
Fídíò
Fídíò
Mo ní ìjàmbá ọkọ̀ nígbà mọ́kànlá, mo si ro ará mi pin láyé pé ó ti parí- Adeola Testimony
30 Ìgbé 2024
Ọmọ mẹ́wàá ni Ọlọ́run fún mi ṣùgbọ́n méje ló jáde láyé nípasẹ̀ ààrùn Measles- Olùṣọ́-Aguntan Adio
29 Ìgbé 2024
7:29
Fídíò,
Egypt ni Orunmila kọ́kọ́ dé sí kó tó rìn wá sí Ile Ife, Ife kọ́ ni olùdáyé- Babaláwo
, Duration 7,29
28 Ìgbé 2024
3:50
Fídíò,
Ṣé bí adẹrìn-ínpòṣónú Layi Wasabi ṣe mú lẹ́nu ló láyà tó?
, Duration 3,50
27 Ìgbé 2024
3:16
Fídíò,
"Ẹ̀rù máa ń bà wá tẹ́lẹ̀ láti farahàn bíi oníṣẹ̀ṣe l‘Oyo, Ọba Adeyemi ló tì wá lẹ́yìn tí ìṣẹ̀ṣe kò fi di àtẹ̀mẹ́rẹ̀"
, Duration 3,16
24 Ìgbé 2024
6:45
Fídíò,
"Mo fi èèpo ẹ̀gẹ́ ṣe èlùbọ́ torí ọ̀dá owó fún àwa méje láti jẹ ọkà, ẹnìkan kú, àwa mẹ́fà dèrò ilé ìwòsàn"
, Duration 6,45
23 Ìgbé 2024
4:11
Fídíò,
Wo ọ̀pọ̀ àkóbá tí òfin ìjọba ń ṣe fún okòwò epo bẹntiró lẹ̀nu bodè Nàíjíríà sí ilẹ̀ Benin
, Duration 4,11
22 Ìgbé 2024
1:34
Fídíò,
'Orí ló kó mi yọ lọ́wọ́ ikú, àwọn ọ̀rẹ́ mi mẹ́rin ni wọ́n pa'
, Duration 1,34
17 Ìgbé 2024
Mo máa kó padà sí Nàìjíríà láti gbé àṣà àti ìrìnàjò wa ga- Pelumi Nubi
16 Ìgbé 2024
5:20
Fídíò,
Ooru tó ń mú ní Nàìjíríà ṣì máa pọ̀ síi jù báyìí lọ àyàfi... - òṣìṣẹ́ àjọ Nimet ṣàlàyé ìdí abájọ
, Duration 5,20
11 Ìgbé 2024
1:29
Fídíò,
Wo ọkùnrin kan tó gbẹ́ kànga bíi ọgọ́rùn ún láti ṣe ìrànwọ́ fáwọn èèyàn ìgbèríko ní Senegal
, Duration 1,29
10 Ìgbé 2024
4:39
Fídíò,
Wo Kábíyèsì Alafo ti ìlú Afo tí í ṣe ọba alayé tó pẹ́ lórí oyè jùlọ lọ́wọ́ yìí nílẹ̀ Yorùbá
, Duration 4,39
9 Ìgbé 2024
5:19
Fídíò,
''Ìrìn wákàtí mẹ́fà la rìn nínú igbó kí ilẹ̀ tó sú bá wa, tí wọ́n sì di ọwọ́, dí ẹ̀sẹ̀ mí mọ́lẹ̀..''
, Duration 5,19
8 Ìgbé 2024
7:38
Fídíò,
Bí mo ṣe rí ọ̀pọ̀ Mílíọ̀nù Nàírà tí mo sì dáà padà fún Ọlọ́pàá lọ́dún 1971 àmọ́ ǹkan t'íjọba sọ rèé - Baba Shonubi
, Duration 7,38
8 Ìgbé 2024
9:23
Fídíò,
Olùdásílẹ̀ ìjọ Celestial ni bàbá mí, akọrin ìjọ ni mí, kí ń tó padà di oníṣẹ̀ṣe - Olorì Papalanto
, Duration 9,23
2 Ìgbé 2024
5:02
Fídíò,
Ogunde ló sọ fún Kunle Afolayan láti fi mí ṣe Baṣọ̀run nínú sinimá Anikulapo - Owobo
, Duration 5,02
1 Ìgbé 2024
4:04
Fídíò,
'Níbo lo ti gbé ọmọ aràrá wa ni bàbá mi kò bá bi ìyá mi' - Aràrá adájọ́
, Duration 4,04
31 Ẹrẹ̀nà 2024
6:54
Fídíò,
'Mo di akọ̀wé àgbà lẹ́nu iṣẹ́ nítorí àwọn òbí kò fi mí sílẹ̀ pẹ̀lú ìpèníjà ara tí mo ní'
, Duration 6,54
30 Ẹrẹ̀nà 2024
5:23
Fídíò,
‘Gbèsè bí i N20million ni ìṣubú Naira kó mi sí, kódà mo ta ilé àti dúkía’
, Duration 5,23
28 Ẹrẹ̀nà 2024
5:17
Fídíò,
'Bíi dìndìnrìn ni mo ṣe bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ Bẹ́skẹ́ tó yọ mi kúrò nínú ìyà àti àìní'
, Duration 5,17
26 Ẹrẹ̀nà 2024
3:29
Fídíò,
Mi ò déèdé yan iṣẹ́ àgbẹ̀ lááyò, ó ní bó ṣe jẹ́ - Arabínrin K.Gold
, Duration 3,29
25 Ẹrẹ̀nà 2024
6:18
Fídíò,
A máa ń ta ẹ̀kú eégún kan ní N400,000, Alaran Egba ṣàlàyé èèwọ̀ tó rọ̀ mọ́ ẹ̀kú eégún rírán
, Duration 6,18
23 Ẹrẹ̀nà 2024
4:43
Fídíò,
Ariwo lásán ni Dádì àti Mọ́mì rò pé mó ń fi ike pa tẹ́lẹ̀, ṣùgbọ́n ó ti sọ mi di èèyàn ńlá báyìí
, Duration 4,43
22 Ẹrẹ̀nà 2024
11:24
Fídíò,
Nítorí kò sí ọ̀nà àbáyọ nínú ìṣẹ́ ní mo ṣe fẹ́ ta ọmọ mi- Sarah ọmọ òrukàn
, Duration 11,24
22 Ẹrẹ̀nà 2024
Ìṣájú
Page
23
nínú
40
1
20
21
22
23
24
25
26
40
Tókàn