BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Awọn ọdọ
Olaleye Paul rí ẹ̀wọ̀n he ní àyájọ́ olólùfẹ́ ní Ilọrin
16 Èrèlè 2022
Ọmọ ọdún 18 dèrò àtìmọ́lé lórí ẹ̀sùn pẹ ó gún akẹgbẹ́ lọ́bẹ pa
15 Èrèlè 2022
"Ẹ̀yin obìnrin, ẹ fi òdòdó ṣe ẹ̀bùn ọjọ́ olólùfẹ́ fún ọkùnrin dípò kẹ gbà kó já òdòdó ara yín"
14 Èrèlè 2022
Ìdí tí mo fi ní ọ́jọ́ ikú ni ọ̀la ọjọ́ 'Valentine' fún àwọn kan- Mike Bamiloye
13 Èrèlè 2022
"Ariwo tí Sofiat pa ló fu ará àdúgbò lára, tí ọwọ́ fi tẹ̀ wá"
6 Èrèlè 2022
Mọ̀lẹ́bí kéde ìsìnkú Tafa Oloyede, bí yóò ṣe lọ rèé
6 Èrèlè 2022
Wo àwòràn ohun tó ṣẹlẹ̀ ní Abeokuta lásìkò ikú Rofiat tí Soliu àti Mustaqim pa
5 Èrèlè 2022
Ìdíje fún sísọ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Yorùbá nílé ẹ̀kọ́ girama dí "Millionaire" lọ́dọọdún gbéra sọ- Yoruba World Centre
5 Èrèlè 2022
Àwọn aláṣẹ ilé ẹ̀kọ́ gíga Adekunle Ajasin sún ìdánwò tó yẹ kó wáyé lónìí síwájú, wọ́n ti iléẹ̀kọ́ náà pa
4 Èrèlè 2022
Oògùn olóró tó lé ní mílíọ̀nù kan la rí gbà lọ́wọ́ àwọn awakọ̀ Onitsha sí Kano- Àjọ NDLEA
3 Èrèlè 2022
5:13
Fídíò,
Òbí ti kùnà nínú ojúṣe, à ń kó àwọn ọmọ yìí lọ sílé ẹjọ́- Oga Ọlọpàá Abimbola Oyeyemi
, Duration 5,13
2 Èrèlè 2022
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́bìnrin méjì tó ń fa shisha l'Ogun ti padà sílé ẹ̀kọ́ wọn lẹ́yìn tí wọ́n ti kọ́kọ́ lọ rọ́kùn ńlé
2 Èrèlè 2022
ASUU Fasiti Obafemi Awolowo fárígá, ìyansẹ́lódì tẹ̀síwájú lórí pínpín owó àjemọ́n;ú àwon Olùkọ́
1 Èrèlè 2022
Tí òògùn owó bá wà nínú Ifa ni, n kò bá ti kọ́ ilé ńlá fún ara mi- Babaláwo
1 Èrèlè 2022
6:30
Fídíò,
O lé ní ogójì obìnrin tó jámikulẹ̀ kí ń tó rí aya fẹ́- Pasito Shanko Alhaji
, Duration 6,30
1 Èrèlè 2022
2:20
Fídíò,
Akàwégboyè Alákàrà
, Duration 2,20
30 Sẹ́rẹ́ 2022
Musulumi àti Kristẹni lo ṣe àdúrà níbi ètò ìsìnkú Timothy Adegoke lónìí
29 Sẹ́rẹ́ 2022
Wo ohun tí ìjọba Oyo ṣe fún ẹni tí ọlọ́pàá SARS lù fọ́ lójú lẹ́yìn àbọ̀ ìgbìmọ̀ EndSARS
27 Sẹ́rẹ́ 2022
Ẹ̀yín àgbà Yorùbá, ẹ dìde yanjú aáwọ̀ òṣèlú láàrin Tinubu àti Osinbajo, bíbẹ̀ẹ́kọ́... - Ajulo
27 Sẹ́rẹ́ 2022
''A kò ní dẹ́kun ìfẹ̀hònúhàn àyàfi tí ìjọba àtàwọn aláṣẹ FUTA bá gbé ìgbésẹ̀ lórí ètò àbò àwa akẹ́kọ̀ọ́''
17 Sẹ́rẹ́ 2022
Wo ọmọ Nàìjíríà mẹ́fà tí ayélujára sọ di ìlúmọ̀ọ́ká
17 Sẹ́rẹ́ 2022
4:02
Fídíò,
Azeez ló tà wá láti Nàìjíríà fún Michael ní Libya kí a tò bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ aṣẹ́wó lẹ́yìn ti mo ta ṣọ́ọ̀bù ọjà mi- Fatimah
, Duration 4,02
17 Sẹ́rẹ́ 2022
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ èèyàn mẹ́rin tó ń jẹ́ ẹran ara èèyàn tí wọ́n tún ń tà ẹ̀yà ara èèyàn
14 Sẹ́rẹ́ 2022
Kìí ṣe ohun tí ojú kò rí rí tí ìyàwó mi bá ní owó jù mí lọ - Kolawole Ajeyemi
8 Sẹ́rẹ́ 2022
Ìṣájú
Page
26
nínú
40
1
23
24
25
26
27
28
29
40
Tókàn