BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idije Liigi
Willian pa itú méje ní ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ rẹ̀ àkọ́kọ́ fún Arsenal
13 Owewe 2020
Atorí ìkan ṣèkan l'Ọlọ́run! De Bruyne gba àmì ẹ̀yẹ Premier League mọ́ Henderson lọ́wọ́
16 Ògún 2020
Liverpool pègúnrẹ́, wọ́n gbé ife ẹ̀yẹ̀ Premier league lẹ́yìn ọgbọ̀n ọdún
23 Agẹmo 2020
Ayé le! Sheffield faṣọ iyì ya mọ́ Chelsea lára lọ́nà ìrìnàjò sí Champions League
11 Agẹmo 2020
West Ham fi omi àbùkù wẹ Chelsea láwọlé sùn, Arsenal yìnbọn pa Norwich
3 Agẹmo 2020
Chelsea dun DJ Cuppy nínú lẹ̀yìn tí Arsenal gba omijé lójú rẹ̀
21 Òkùdu 2020
Ṣé ẹ lè kí Liverpool kú oríire báyìí? Premier League yóò bẹ̀rẹ̀ padà lóṣù kẹfà
11 Èbibi 2020
Ẹ̀rù n ba àwọn agbábọ́ọ̀lù Premier League láti padà sórí pápá nítorí coronavirus
2 Èbibi 2020
Màmá Guardiola d'olóògbé lẹ́yìn tó lùgbàdì Coronavirus
6 Ìgbé 2020
Wọ́n ti wọ́gilé ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ Arsenal àti Brighton lẹ́yìn tí Mikel Arteta lùgbàdì àrùn Coronavirus
13 Ẹrẹ̀nà 2020
Àgunlá! Ohun tó bá wù yín ni kẹ sọ, iṣẹ́ ló ká mi lára - Ighalo
6 Ẹrẹ̀nà 2020
Watford tu ìyẹ́ apa Liverpool
29 Èrèlè 2020
Lampard àtàwọn agbábọ́ọ̀lù Chelsea dọ́wọ́jọ di ẹrù wíwo lé Mourinho àti Tottenham lórí
22 Èrèlè 2020
Wo ìdí tí Man U ṣe já Odion Ighalo sílẹ̀ nínú ìgbáradì rẹ̀ tí yóò wáyé ni Spain
8 Èrèlè 2020
Odion Ighalo darapọ mọ́ ikọ̀ Manchester United, òjijì ló bá àwọn olólùfẹ́ rẹ̀
1 Èrèlè 2020
Liverpool fi ojú Manchester United gbolẹ̀ ní Anfield
19 Sẹ́rẹ́ 2020
Màá ra Arsenal ní 2021 tí mo bá kọ́ iléeṣẹ́ ìfọ́po rọ̀bì tán - Dangote
13 Sẹ́rẹ́ 2020
Iheanacho gba Leicester city lọ́wọ́ ìtìjú agbolé
9 Sẹ́rẹ́ 2020
C. Ronaldo fi góòlù mẹ́ta bẹ̀rẹ̀ ọdún 2020
6 Sẹ́rẹ́ 2020
Van Persie gbàgà lẹ́nu rẹ! Solskjaer fárígá lẹ́yìn tí Van Persie ló ń rẹ́rìn-ín
4 Sẹ́rẹ́ 2020
Chelsea kò rọ́wọ̀ mú lẹ́yìn tí Southampton dáná sun Stamford Bridge
27 Ọ̀pẹ̀̀ 2019
Àgùtàn Arsenal kò tíì paṣọ èṣí dà lábẹ́ Mikel Arteta
27 Ọ̀pẹ̀̀ 2019
Inú mi dùn láti darapọ mọ́ ikọ̀ Arsenal -Mikel Arteta
20 Ọ̀pẹ̀̀ 2019
Òkété ti bórù! Manchester United fọ́ Manchester City lẹ́nu pẹ́tẹpẹ̀tẹ mọ́lé
7 Ọ̀pẹ̀̀ 2019
Ìṣájú
Page
4
nínú
6
1
2
3
4
5
6
Tókàn