You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n
Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.
Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́
Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo
Amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ Akeredolu tó gbá ìyàwó mi létí ó bá má lọ lọ́fẹ̀ẹ́ - Ọkọ Aláboyún
Àwọn agbébọn tún ti jí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ míì gbé ní ìpínlẹ̀ Abia
Wo ohun tó fa ti kòkòrò àrùn COVID-19 tuntun ní India ṣe búrẹ̀kẹ̀
Àfinra! Amotekun lé àwọn Fulani 137 tó gba inú igbó ìjọba lọ́nà àìtọ́ kúrò l'Ondo
Kéére o! Àwọn ọmọ Yorùbá náà ti bẹrẹ sí ni dáná sun òkú ní Nàìjíríà, bí wọ́n ṣe ń ṣeé rèé
Haram ni kí èèyàn máa san owó ìtúsílẹ̀ fún àwọn ajínigbé - Sheikh Ibrahim Maqari
Ọjọ́ mẹta péré lo ní báyìí láti ṣe àyẹ̀wò Covid19 ṣáájú ìrìnàjò wá sí Nàìjíríà!
Bola Tinubu: Ọlọrun kò ní gbà kí Naijiria tún la ogun abẹ́lé míràn kọjá
Wo ìdí tí ìjọba Naijiria ṣe fòfin de gbogbo arìnrìnàjò láti India, Brazil àti Turkey
Buhari, wá nǹkan ṣe sí ètò àbò tó mẹ́hẹ ní Naijiria kó tó pẹ́ jù - Alaafin, Ooni
A kò bá ti lé Baba Ijesha àmọ́ kìí ṣe ọmọ ẹgbẹ TAMPAN, a kò sì fọwọ́ sí ìwà tó hù - Mr Latin
Àwọn alákòso BCOS tan ìmọ́lẹ̀ sí ọ̀rọ̀ iléègbé àwọn òṣíṣẹ́ tí ìjọba ìpínlẹ̀ Oyo bẹ̀rẹ̀ sí ń wó
Wo àwòdamiẹnu àwòrán Mọ́ṣáláṣí Ànọ́bì ní Medina!
Irọ́ lásán ni pé èèyàn 25 bọ́ sọ́wọ́ ajínigbé ní òpópónà Igboọra sí Eruwa - Ọlọ́pàá Ọyọ
A ti wà nínú igbó láti ṣàwárí àwọn mẹ́ta tí wọ́n jí gbé ní Ikaramu Akoko - Amotekun Ondo
Wo àwọn nkan tó yẹ́ kí o mọ̀ nípa Olufon, Ọba Adekunle Magbagbeola tó wàjà
Tani Mahamat Kaka Idriss Deby tó di aàrẹ̀ tuntun ilẹ̀ Chad lẹ́yìn ìṣekúpani bàbá rẹ̀?
Ọba tí wọ́n jí gbé l'Ekiti gba òmìnira lọ́wọ́ àwọn ajínigbé
A ti ṣetán láti fi ẹ̀mí wa lélẹ̀ fún òmìnira ilẹ̀ Yoruba, a ò níbi kankan ti a fẹ́ sálọ - Ọba Adetokunbo Tejuosoho