You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.

Take me to the main website

Ìjíròrò láàrin àwọn olùdíje sípò gómìnà ìpínlẹ̀ Ọyọ

Ìròyìn àti àlàyé lórí ìjíròrò láàrin àwọn olùdíje sípò gómìnà ìpínlẹ̀ Ọyọ láti gbàngàn UCH ní Ibadan

Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́

Abdulwasiu Hassan

  1. Adebayo Adelabu,ẹgbẹ́ òṣèlú APC

    Penkẹlẹmẹsi ni orúkọ̀ tí àwọn èèyàn máa ń pè Adebayo Adelabu èyí tó jẹ́ orúkọ ìnagijẹ Bàbá rẹ̀ tó jẹ́ ìlúmọ̀ọ́ká olóṣèlú nípínlẹ̀ Ọyọ nígbà kan rí.

    - Wọ́n bíi ní ọjọ́ keèjìdínlọ́gbọ̀n, oṣù kẹẹ̀sàn án, ọdún 1970 - Ó jẹ́ igbákejì Gómìnà, Bánkì àpapọ̀ Nàìjíríà (CBN)- Ọmọ agbègbè Kudẹti ní ìlú Ibadan - Akẹkọgboye ninu imọ Iṣiro owo lati fasiti Obafemi Awolowo ni. - Ọmọ ẹgbẹ ajọ Institute of Chartered Accountants of Nigeria (ICAN) nii ṣe.

  2. Olùdíje fún ipò gómìnà lábẹ́ ẹgbẹ́òṣèlú Zenith Labour Party, ZLP, Sharafadeen Alli kò wá sí ìpàdé ìtagbangba BBC Yorùbá pẹ̀lú àwọn olùdíje fún ipò gómìnà ní ìpínlẹ̀ Ọyọ. Ó ti kọ́kọ́ jẹ́ẹ̀jẹ́ péòun yóò wà á.

  3. Ẹ káàbọ̀

    Ẹ káàbọ̀ sí òpó tí yòó fún yín ní ìròyìn b'óṣe ń lọ níbí ìjìròrò láàrin àwọn olùdíjesípò gómìnà ìpínlẹ̀ Ọyọ.