You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Níbo layé kọjú sí?: Ìdí táwọn gbajúmọ̀ kìí ṣe ń ṣèrànwọ́ fáwọn èèyàn àti ohun tójú 'singlemother' ń rí láwùjọ̀
Níbo layé kọjú sí?: Ìdí táwọn gbajúmọ̀ kìí ṣe ń ṣèrànwọ́ fáwọn èèyàn àti ohun tójú 'singlemother' ń rí láwùjọ̀
Published
Koko ọrọ meji to n maa n fa arojinlẹ edeaiyede ati ọrọ awisọ lawujọ la mu wa lori eto ọlọsọọsẹ wa nibo laye kọju si lọsẹ yii.
Ọpọ igba lawọn eeyan maa n sọ pe awọn gbajumọ kan lahun ati pe wn kii fẹ ṣoore. Amọṣa ṣa nigba ti a ju ibeere yii si gbajumọ oṣere, Ajanbadan, o sọrọ ilẹ kun lori awọn idi to n fa eyi.
Bakan naa la tun fọn si igboro lati gbọ ohun ti araalu ni sọ lori ipenija awọn obinrin ti wọn bimọ ṣugbọn ti wn ko si labẹ ọkọ nitori idi kan tabi omiran.
Hmmmm...ju gbogbo rẹ lọ ẹ wo fidio yii ki ẹ gba mulo nibẹ