Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Njẹ o mọ iye ti yoo gori owo ipe ati data to n ra pẹlu afikun tariifu ida aadọta tijọba buwọlu?
Bunmi gbọ o
Ipe ori foonu to n lo N11 fun tẹlẹ yoo di N16.50, bẹẹ ni data giigi kan N1000 tẹlẹ yoo di N1,500
Atẹjiṣẹ ori foonu n kọ?
Kan soju opo BBC Yoruba,Com/Yoruba fun ẹkunrẹrẹ
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Kabiyesi, ẹ fiye denu, ẹ fori jin mi gbogbo ẹṣẹ to ba ṣẹ yin
Oriade wo lo ṣẹ to fi n tuuba bayii?
Emi ma kọ, Imaamu agba Sheikh Teliat Ayilara lo ma tọrọ aforojin lọwọ Soun ilu Ogbomoso, Ọba Ghandi Afolabi Olaoye lẹyin aawọ to ti wa laarin wọn
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Omi tuntun ti ru, ẹja ti tuntun ti wọ ọ lorilẹede Amẹrika
Bẹẹ ni...lara awọn iwe aṣẹ ti Aarẹ Donald Trump buwọlu lẹyin ti wọn bura fun un tan ni pe
ẹya akọ ati abo nikan ni ẹya iṣẹda ti ijọba orilẹede Amẹrika yoo da mọ
kinni yoo wa ṣẹlẹ sawọn to n ṣakọ-ṣabo atawọn to n ṣabo-ṣakọ?
Ti o ba fẹ mọ...


