Àwọn ohun tí o lè ṣe rèé láti mú kí ọmọ rẹ má a jẹ èso àti ewébẹ̀ dáadáa

Àwọn ohun tí o lè ṣe rèé láti mú kí ọmọ rẹ má a jẹ èso àti ewébẹ̀ dáadáa
Published

Ọpọ obi lo maa n ṣọrọ pe awọn ọmọ wọn kii fẹ jẹ eso ati ewebẹ daadaa ti wọn si ti fi awọn nnkan miran rọpo rẹ ni jijẹ.

Bi o tilẹ jẹ wi pe awọn obi kan n wo o gẹgẹbi aṣọ igba la n da fun igba ati pe bi awọn ọmọ ode oni ṣe fẹ ni, sibẹ eyi ko da ọwọ pataki iṣẹ ti eso ati ewebẹ n ṣe lara, paapaajulọ awọn ọmọde duro.