Akomolede: Akuko Gagara ni ìwé tó ṣàfìhàn ohun tó ń ṣẹlẹ̀ ní Nàìjíríà lásìkò yìí- Fatimo Bola Owokunle

Àkọlé fídíò, Akomolede: Akuko Gagara ni ìwé tó ṣàfìhàn ohun tó ń ṣẹlẹ̀ ní Nàìjíríà lásìkò yìí- Fatimo B
Published

Lere Adeyemi ṣe adape orukọ si Ajuba ati Aromire dipo Abuja ati Eko.

Iwe Akuko Gagara ti ko fẹ ki akukọ kekere mii kọ ni iwe ti a n gbeyẹwo lonii lori eto Akomolede ati aṣa lori BBC Yoruba.

Onkowe naa kọ iwe naa nipa fif ṣe afiwe ohun to n ṣẹlẹ laarin awọn oloselu, lọbaloba ati ara ilu Naijiria.

Itan in iwe naa ni o pa owe fun gbogbo awọn eeyan Naijiria ati oṣelu jẹgudujéra ti ko fẹ ki ọkan mékunnu balẹ.

Awọn afipagbajọba ati ipa awọn olowo lawujọ naa jẹ jade.

akuko gagara

Alhaja Fatima Bola Owokunle lati ile ẹkọ Kwara State College of Arabic.

Itan naa lo ni awọn ẹda itan bii Dende, Alaasa to je igbakeji rẹ. Osoru ati bẹẹ bẹẹ lọ.