Awọn n so igi mo ẹgbẹ oke gogooro ti Huashan ni Ariwa-Iwọ oorun orilẹede China.
Published
Isẹ to lewu ni ki eniyan ma a tun ọna se lori oke gogoro, eleyii ti ki n se fun awọn olojo.
Bẹ ẹ gẹgẹ ni ọrọ naa ri fun awọn osisẹ to n n so igi mọ ẹgbẹ oke gogooro ti Huashan ni Ariwa-Iwọ oorun orilẹede China.
Awọn osisẹ naa n fi igi se oju ọna fun awọn arinrinajo ti wọn ma n wa si oke naa lati wa gbafẹ.