You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.

Take me to the main website

Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n

Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.

Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́

Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo

  1. Ṣé o mọ̀ pé o leè forúkọ̀ iléeṣẹ́ rẹ̀ sílẹ̀ lọ́fẹ̀ẹ́? Oníṣẹ́ àdáni 250,000 ni ìjọba ṣe ìlànà yìí fún

  2. Àgbàrá òjò gbé alága àdúgbò àti èèyàn méjì mìí lọ nílùú Ibadan

  3. Àjẹ́ ké lánàá, ọmọ kú lónìí ni ọ̀rọ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ Lekki Tollgate - Bode George

  4. Àwọn tó mọ̀ nípa ìpànìyàn Lekki yóò fojú winá òfin - Sanwo-Olu sí Becky Anderson

  5. Afurasi 409 tó jí ẹrù ẹlẹ́rù kó lẹ́yìn ìwọ́de EndSARS l'Abuja, Ilorin, Ondo ti kó sọ́wọ́ Ọlọ́pàá

  6. Akinwumi Isola dárà nínú ìwé "Nítorí Owó" lórí Akomolede Yoruba

  7. Iyabo Ojo gé okùn àjọṣepọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú olóṣèlú nínú ẹgbẹ́ APC ati PDP

  8. Àwọn ọbá aláye ilẹ̀ Yorùbá márùn-ún pẹ̀lú ọ̀pá àṣẹ wọn

  9. Irọ́ ní pé bàbá wa, Soun Ogbomoso paradà di ọmọ tuntun, báyìí ni àwọn ọ̀rẹ́ ṣe dalẹ̀ rẹ̀ tí wọ́n pa á

  10. Agbára wa kò ká àrùn Covid-19 mọ́ - Ìjọba ilẹ̀ Amẹrika

  11. Iléèṣẹ́ tẹlifísàn AIT, Arise TV àti Channels wọ gàù àjọ NBC nítorí ìpànìyàn Lekki

  12. Àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ Britain fi ṣìkún òfin mú àwọn Nàìjíríà tó ń gbìyànjú láti sá wọ ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì

    Awọn ọmọ iṣẹ ologun ilẹ Gẹẹsi ti fi ṣẹkẹṣẹkẹ ofin mu awọn ọmọ Naijiria meje to n gbiyanju lati salọ silẹ naa ninu ọkọ oju omi elepo kan.

    Lara awọn oṣiṣẹ inu ọkọ oju omi Nave Andromeda naa lo ke gbajare lẹyin ti awọn eeyan to n gbiyanju lati salọ naa halẹ mọ wọn.

    Eyii to mu ki minisita eto abo ilẹ Gẹẹsi ran awọn akọṣẹmọṣẹ ọmọ ogun, Special Forces, lọ sinu ọkọ naa lẹyin ti wọn ni o ṣeṣe ki awọn eeyan ọhun gbiyanju latoi ja ọkọ naa gba lọwọ awọn to n tukọ rẹ.

    Ko pẹ si asiko naa ti ileeṣẹ to n ri si ọrọ abo ilẹ ọhun kede loju opo Twitter rẹ pe “awọn ọmọ ogun ti gba iṣakoso ọkọ oju omi naa, wọn si ti fi papnpẹ ofin mu awọn afurasi meje.”

    Ileeṣẹ iroyin ilẹ Gẹẹsi kan so pe awọn ọmọ ogun mẹrindinlogun lo yabo ọkọ oju omi ọhun lati doola ẹmi awọn to wa ninu rẹ.

    Ṣaaju ni Balogun ọkọ oju omi naa ti ke sita nigba to ni oun ro pe ẹmi awọn ero ọkọ ọhun wa ninu ewu.

    Oṣiṣẹ eto abo ori omi kan tilẹ sọ pe, ọkọ ofurufu ẹlikọpita meji tẹle awọn sọja ti wọn ran lati doola ẹmi awọn ero ọkọ naa.

    Ṣugbọn awọn agbẹro ileeṣẹ to n ṣakoso ọkọ naa, Tatham & Co., ti sọ fun BBC pe kii ṣe pe awọn afurasi naa ni erongba lati ja ọkọ ọhun gba.

    Ni bayii, minisita eto abo ilẹ Gẹẹsi, Ben Wallace, ti sọ pe iwadii ti bẹrẹ lori iṣẹlẹ naa.

  13. Taa gan ló ni Lekki Toll gate láàrin aráàlú àti Asiwaju Tinubu?

  14. Wo ohun tí Fashola rí níbi ìṣẹ̀lẹ̀ Lekki Tollgate tó ń fa ariwo lórí ayélujara

  15. Wo nkan tó yẹ́ kí o mọ̀ nípa Adeyinka Godson tó fún ẹ̀yà Igbo ní wákàtí 48 láti kúrò nílẹ̀ Yorùbá

  16. Àfi kí ICPC wú ìdí tí ìjọba kò fi pín ǹkan ìrànwọ Covid-19, táráàlú ń jí i kó jáde - SERAP

  17. Ojú àwọn tọ́wọ́ ti tẹ̀ lára àwọn tó jí 'tíá rọ̀bà ọ̀kadà', fíriìjì, ẹ̀rọ ata kó nílée Sẹ́nétọ̀ Teslim Folarin rèé

  18. Wo àwọn ayédèrú ìròyìn tó gbà'gboro kan lásìkò ìwọ́de #EndSARS

  19. Àwọn ọ̀nà láti dẹ́kun ìwọ́de ọ̀dọ́ lọ́jọ́ iwájú nìyí

  20. Èèyàn 229 ló ti wà ní gbaga òfin fún wàhálà tó wáyé l'Eko