Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Tinubu ti jaa araalu kulẹ, Ile le
Joshua, gbaga lenu re?
Emi ke, Aare Ona Kakanfo lle Yoruba, Iba Gani Adams lo so bee ninu leta kan ko si Aare Bola Tinubu pe
O ti ja araalu kule pelu afikun owo epo bentiroolu ati owongogo nkan to gboc
Iba Gani Adams soro ile kun, Kan si oju opo BBC.com/Yoruba fun ekunrere
Omiyale agbara ya soobu
Arọọda ojo to wo daamu omi lule ni Maiduguri nipinle Borno ti fa ekun on
Eyi to ti so opo eeyan di alainile lori, Koda awon eranko to wa ninu ogba lom naa tun ti le sita bavii
ljoba ni o ti pe ogbon bayii ti iru isele ohun ti waye nipinle Borno
Keleduwa gba wa nbe
lle ejo giga niluu Abuja ti fawon oluwode ebi n pa wa to wa lahamo ni beeli pelu milonu mewaa naira fun eni kookan
Awon afurasi mewaa naa ni won n jejo lori sun iditemojoba
ekunrere iroyin hun loju opo BBC.COM/Yoruba
