Kò ṣeè má gbọ̀ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣeè má gbọ̀ọ́
Kò ṣeè má gbọ̀ọ́
Published

Oniṣẹṣe to dana sun Kuraani dero atimọle n'Ibadan

Ki lo wa ri lọbẹ to fi gaaru ọwọ?

Iyẹn naa lo n ya ọpọ eeyan lẹnu

Mo gbọ pe ariyanjiyan laarin oun ati eeyan kan lo fa sababi

Bẹẹni, Amọ ṣa, ọkunrin ọhun ti wa lahamọ ajọ DSS bayii

Kan soju opo BBC fun ẹkunrẹrẹ

**

Nọọsi alabẹrẹ to n fi ede Yoruba kọ araalu nipa ilera ara wọn ba BBC YORUBA sọrọ

Eyi tun gbẹnu tan o, ede Yoruba bii ti bawo?

Adejoke Ogunbiyi sọ fun BBC pe e

Oun fẹ ki awọn araalu mọ nipa awọn idape ede oyinbo to wa ninu agọ ara ye wọn yekeyeke

Bakan naa lo ni ọpọ awọn eeyan maa n fẹ koun sọ nipa oogun ti wọn le lo fun ọrọ ilera wọn

Eeti jẹ?

***

Ijọba Naijiria sọ pe Owo ipe ati data yoo lọ soke laipẹ

Njẹ wahala ko tun de bayii?

Rara o! Minisita feto ikansira-ẹni lawọn ko nii jẹ ki owo naa lọ soke si ida ọgọrun ti awọn ileeṣẹ ikansira-ẹni n beere fun un

O ni agbekalẹ ilana ti awọn yoo gbe jade ko nii jẹ kawọn ileeṣẹ ibara-ẹni sọrọ fowo kun owo wọn bo ba ṣe wu wọn