Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Published

Kí lo ṣe ẹ to o ka gongo bayii?

A ni pe ẹgbẹlẹgbẹ owo ni mo padanu sinu okoowo Cbex?

Ki lo n jẹ bẹẹ?

Okoowo ori ayelujara crypto kan ma ni, ti mo darapọ mọ loṣu meji sẹyin amọ ti wọn ti kogba sile bayii

Ha! Mo gbọ ti wọn n sọrọ nipa rẹ amọ ko ye mi daadaa

Kan soju opo bbc.com/yoruba lati ka ẹkunrẹrẹ iroyin lori rẹ

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Awa o faramọ piparapọ mọ ẹgbẹ oṣelu kankan lori eto idibo 2017

Awọn gomina ẹgbẹ oṣelu PDP lo sọ bẹẹ nibi ipade apero wọn to waye niluu Ibadan lọjọ

Eyi lo n waye lẹyin ti eekan ẹgbẹ naa, Atiku Abubakar ti ṣaaju sọ pe

Awọn n ṣiṣẹ pẹlu awọn ẹgbẹ alatako miiran lati yẹ aga mọ Tinubu nidii lọdun 2027

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Gbajumọ olorin Habeeb Okikiola ti ọpọ mọ si Portable sun ọgba ni Ilorin

Nitori ko ri eeyan ṣe oniduroo fun-un lati maa lọ jẹjọ ẹsun ibanilorukọjẹ ti Saheed Osupa fi kan an

Lawọn aṣọgba ẹwọn ba yọ abẹ ti irun alaranbara ori rẹ ti wọn si fa gbogbo rẹ lọ

Nitori ki ni?

Fun ẹkunrẹrẹ alaye

Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́