Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Published

Gbọ na, ta lo sọ ina si ile ẹjọ giga to wa niluu Ilesha nipinlẹ Osun

Hmmm... Bẹẹ laa bini o

Ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ ile ẹjọ, JUSUN, ipinlẹ Osun sọ pe igba kẹta ree ti irufẹ iṣẹlẹ bẹẹ yoo waye

Ẹṣio!

Wọn ni awọn kan tiw kọkọ sọ ina sile ẹjọ ọhun lọun 2017 ati ati 2021

Duro na, ki wa ni ọlọpaa sọ?

Kan soju opo BBC Yoruba fun ẹkunrẹrẹ

____________________________

Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ondo ti bẹrẹ iwadii lori iku OgoOluwa Ọmọ́gẹ̀, to jẹ ṣe ọmọ-ọmọ gbajugbaja olorin, Comfort Ọmọ́gẹ̀, to ti di oloogbe

Ọlọpaa sọ pe ọkunrin kan to n ṣagolo kaakiri lo gun oloogbe naa lọbẹ niluu Okitipupa, to si gba ibẹ ku.

____________________________

Awọn agbebọn ti ṣekupa ọmọ Naijiria kan to n ṣiṣẹ awakọ Uber, Olatunji Bolaji, niluu Philadelphia, lorílẹ̀èdè Amẹ́ríkà

Ẹrọ CCTV ṣafihan pe ẹnu iṣẹ ni Bolaji wa ti wọn fi dana ibọn ya oun ati ero ọkọ rẹ

A gbọ ibọn ba ero ọkọ naa ni apa, ẹsẹ ati ikun amọ Bolaji dero ọrun

Fun ẹkunrẹrẹ iroyin yii atawọn iroyin mii....