Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Hmmmmmm
Ki le ṣe ọ to n mi kanlẹ bayii
Emi naa kọ o, iroyin to tẹ wa lọwọ ọjọ Ẹti lo sọ pe, Aya Gomina ipinlẹ Akwa Ibom, Patience Umo Eno ti dagbere faye lẹyin to ṣaisan
Kọmiṣọna fun eto iroyin nipinlẹ naa, Ini Ememobong lo kede iku rẹ lori itakun ayelujara
Ekunrere wa loju opo BBC.com/Yoruba
Ko si ṣiṣe ko ṣai sẹ, awọn onibara mi yoo pẹjọ kotẹmilọrun
Awọn lawọn onibara rẹ ẹ?
Agbẹjọro awọn adigunjale to fọ banki niluu Offa t’ileẹjọ ni ki yẹgi fun lo maa sọ bẹẹ.
Eeyan to le lọgbọn lo padanu ẹmi wọn nibi iṣẹlẹ ọhun
Fun ẹkunrẹrẹ iroyin, kan soju opo BBC.com/Yoruba
Meji ninu awọn Ọga ajọ to n ri si ọgba ẹwọn ni Naijiria
nijọba ti sọ pe ki wọn lọ rọkun nile bayii
Lori ọrọ to jẹyọ ninu fọnran kan eyi to gbe ohun Bobrisky jade
Nibi to ti fẹsun kan ọga ajọ naa pe baba isalẹ oun ba a sọrọ
Lati foun sinu ile kan dipo ọgba ẹwọn
