Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Published

Iyawo aarẹ ile igbimọ aṣofin agba Naijiria tẹlẹ, Beatrice Ekweremadu,

Ti gbominira lọgba ẹwọn nilẹ Gẹẹsi

Lọdun 2023 nile ẹjọ kan ni UK ju u sẹwọn pẹlu ọkọ rẹ lori ẹsun lilo ẹya ara eeyan lọna ti ko bofin mu

ṣe ọkọ rẹ naa ti wa gbominira lọgba ẹwọn?

Tete lọ sori ikanni BBC Yoruba fun ẹkunrẹrẹ

''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Ijọba o ni kawọn ẹṣọ oju popo maa fipa mu ọkọ o

Ọga agba ajọ ẹṣo oju popo tẹlẹ ri nipinlẹ Oyo, Ọgagun Rasaki Salawu lo sọ bẹẹ

Ajagunfẹyinti Salawu sọ fun BBC Yoruba wi pe

mimu nọmba ọkọ lasan ni ọna ọmọluwabi ti ofin la kalẹ fawọn oṣiṣẹ ajọ ẹṣọ oju popo

'''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Ki lo le mu keeyan to gbominira lọgba ẹwọn tun dero ẹwọn pada na

Iyẹn to tun gbẹnutan o, ẹfun abi eedi?

Sunday Omisakin to wa lara awọn ẹlẹwọn ti Gomina ipinlẹ Osun da silẹ loṣu to lọ nile ẹjọ majisireeti kan niluu Osogbo tun ti ju sọgba ẹwọn pada

Lori ẹsun wi pe o ji ẹrọ amohunmaworan lẹyin ọjọ mẹjọ to kuro lọgba ẹwọn.

Fun ẹkunrẹrẹ......

Aworan