Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
A o riru eyi ri, a fi n deru ba ọlọrọ ni
Ṣugbọn iṣẹlẹ iku tọkọ-taya ti wọn pa ara wọn l'Ekiti yii kọja bẹẹ o
Inu agbara ẹjẹ lawọn mejeeji sun, nnkan ọmọkunrin ọkọ ko si nibẹ mọ, wọn ṣa agbari iyawo naa yankan-yankan
Ṣe awọn naa ni wọn si kun ara wọn bi eyi?
Alaye ohun toju wa to wa loju opo BBC.com/yoruba
nnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnn
Habeeb Okikiola ti ọpọ mọ si Portable, ti foju ba kootu loni
Ile ẹjọ majsireeti Ogun ni wọn ti ṣafihan rẹ lori ọrọ awọn agbefọba ileeṣẹ aato ilu ti wọn lo fiya jẹ l'Ota
Ile ẹjọ ti gba beeli rẹ pẹlu miliọnu meji naira, won si ni ko gbọdọ..
Ko gbọdọ ṣe kin ni?
Lọ soju opo bbc.com/yoruba
--------------------------------------------------------------------------------------------
Òòyẹ̀ kan kò lè yẹ ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀ l'Ọsun lọjọ Satide
Ṣe pẹlu rogbodiyan to ṣẹlẹ yii naa?
Alaga ajọ eleto idibo ipinlẹ Ọsun OSIEC ni awọn ti ṣetan
AAbo nkọ?
Awọn ọlọpaa lawọn ti mura tan
Awọn ẹgbẹ oṣelu nkọ o
PDP lawọn ti n ganu de ibo naa , amọ APC ni awọn o ṣe
Fun alaye kikun

