Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Wo o, Sunday Igboho kan lọ fi akoko rẹ ṣofo lori iwe to kọ si ijọba UK
Ẹhn gbaga lẹnu ẹ Faoziyah?
Joshua, emi kọ o, amofin agba kan ni Naijiria, Monday Ubani lo sọ bẹẹ
Ubani sọ fun BBC News Yoruba pe ijọba ilẹ Gẹẹsi ko le ṣe nnkankan lori idasilẹ Yoruba Nation amọ o
Amọ kini?
Kan si oju opo bbcnews.com/Yoruba fun ẹkunrẹrẹ
Ẹ kaabọ, ẹ kaare, bakọni ṣe maa n ṣe lẹ ṣehun
Ta lo n ki to n ki i ni mẹsan an mẹwaa?
Aarẹ Bola Ahmed Tinubu lo maa gboṣuba kaare fawọn ikọ Super Eagles lẹyin ti wọn pada sile lati Libya
O ni ohun to buru jai ni iriri tawọn agbabọọlu naa ni ni papakọ ofufuru Libya
Tinubu wa rọ ajọ CAF pe ko ṣewadii iṣẹlẹ naa pẹlu ijiya to tọ
Ọmọ ọdun mẹẹdogun kan, Chinaemere Opara ti pe ajọ JAMB, Minisita feto ẹkọ, ati NUC lẹjọ
Lori ofin to sọ pe ọmọ ti ko ba i tii pe ọdun mejidinlogun ko le wọ ile ẹkọ giga
Fun ẹkunrẹrẹ awọn iroyin yii
