Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Àìríṣẹ́ṣe pọ̀ si ní Nàìjíríà bí báńkì CBN tún ṣe se àfikún èlé orí owóyáá sí 27.25%
Ti ọpọ awọn olokowo si n pariwo pe eyi yoo ipalara fun idokowo ati idagbasoke ọrọ aje Naijiria
Bakan naa, Ajọ NBC kede pe ida marun ati diẹ ọmọ Naijria ni ko nisẹ lọwọ ni oṣu kẹta akọkọ ọdun 2024 yii.
Ki wa ni ọna abayọ bayii
Alaye wa loju opo BBC.COM/Yoruba
//////////////////////////////////////////
N jẹ ẹ o ti gbọ Akinlabi ?
Pe kin tun ni dakun Joshua
Pe o dabi ẹni pe gbajumọ ọkunrin to maa n mura bi obinrin, Idris Okuneye ti ọpọ eeyan mọ si Bobrisky
Tun ti kan ijangbọn mii lọdọ ajọ EFCC tori ẹsun gbigba riba miliọnu mẹẹdogun Naira to fi kan awọn osisẹ kan ninu ajọ naa
Ajọ EFCC si ti ranṣẹ pe e wi pe ko wa sọ tẹnu rẹ lori fọnran naa to lu sori ayelujara
kan si oju opo BBC.COM/Yoruba fun ẹkunrẹrẹ iroyin naa
