Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Ile igbimọ aṣofin Oyo ti bẹrẹ igbesẹ ti yoo sọ Alaafin di alaga igbimọ lọbalọba Oyo titi lae.
Olubadan yoo di igbákejì, Soun, ipo kẹta
Ṣugbọn Ibadan ti lawọn o gba o
Atẹjade Aarẹ Mogaji ilẹ Ibadan, Nurudeen Akinade, sọ pe Ibadan ki i ṣe igbakeji Oyo .
Wọn kilọ fun ile igbimọ lati ma da wahala silẹ
Ẹkunrẹrẹ wa ni BBC.COM/YORUBA
………………………………………………………………
Awọn obi figbeta nitori atunṣe Jamb to dapọ mọ WAEC
Lẹyin ti Jamb kede atunṣe UTME to bẹrẹ loni ọjọ Ẹti
BBC de awọn ibudo atunṣe idanwo kan l'Eko, atunṣe naa si waye.
Ṣiṣe jamb mọ waec, ewu ọna, ati bawọn akẹkọọ kan ṣe ti kuro nipinlẹ wọn wa lara ẹhonu awọn obi.
Ẹkunrẹrẹ wa loju opo wa
,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,
"Ọgbẹ́ ọkàn ló jẹ́ pé ọmọ mi para ẹ̀ tórí èsì ìdánwò JAMB"
Opesusi Oluwafemi, Baba Oloogbe Faith Opesusi to jẹ majele n'Ikorodu nitori esi idanwo 146 lo so bẹẹ fun BBC.
O ni maaki ti jamb fun ọmọ oun oun ki i ṣe tiẹ.
Fun ẹkunrẹrẹ

