Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ifilọlẹ eto ti ijọba orilẹede Brazil ṣe lati fopin si ebi ati iṣẹ lagbaaye
Wa n’ibamu pẹlu erongba ijọba mi ni Naijiria
Aarẹ Bola Tinubu lo sọrọ yii nibi ipade awọn olori orilẹede G20 eyi to n lọ lọwọ ni Brazil
Tinubu sọ nibi apero naa pe ijọba oun ṣetan lati ri pe iṣẹ ati oṣi di ohun igbagbe ni Naijiria.
‘’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’
Oludije sipo gomina fẹgbẹ oselu PDP nipinlẹ Ogun ninu idibo ọdun 2023, Ladi Adebutu, ti dero ahamọ ajọ ọtẹlẹmuyẹ DSS
Kinni wọn lo ṣe?
Akọwe ẹgbẹ oṣelu PDP nipinlẹ Ogun, Kayode Adebayo sọ pe DSS ransẹ pe Adebutu fun ifọrọwerọ lori rogbodiyan to waye lasiko eto idibo ijọba ibilẹ to waye lopin ọsẹ to kọja
Ẹkunrẹrẹ wa loju opo BBC.Com/Yoruba
‘’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’’
Iku pa Abiri, Abiri lọ, iku p’Abiri, Abiri rọrun
Ta lo tun kuu?
Oloye Sunday Babatunde to n gbe eegun Danafojura, eegun to n fina wẹra bi omi l’Ogbomoso lo jade laye
Fun ẹkunrẹrẹ lori ohun to ṣokunfa iku Oloye Babatunde...


