Paystack Shola Akinlade: Ìgbésẹ̀ 5 yìí ni mo gbé tíléeṣẹ́ Stripe fi dókòwò $200m pẹ̀lú mi
Published
Lasiko ajakalẹ arun Coronavirus ta wa yii, ọpọ ọrọ aje orilẹede ati tawọn idile lo ti dẹnukọlẹ, ti airisẹse si gbode.
Amọ ọna kan wa ti eeyan fi le ri taje se lai se laala pupọ, ọna yii si ni amulo awọn oju opo kan lori ayelujara fun okoowo.
Onimọ kan nipa imọ ori ayelujara, Shola Akinlade salaye fun BBC nipa igbesẹ marun ti oludokowo lori ayelujara kan gbọdọ gbe, ko to le lu aluyọ.
Àwọn ìtàn mánigbàgbé tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ìtàn ayé Henry Fajemirokun, olówó tó fi owó mọ Olúwa àti ènìyàn
- Ìtàn ayé Taiwo Oredein rèé, àgbà òṣèlú tó parí ayé rẹ̀ sọ́gbà ẹ̀wọ̀n
- Ìtàn ìgbé ayé Bode Thomas rèé, ó kọ́ wa láti máa kó ẹnu wa ní ìjánu
- Ṣo mọ̀ pé J.F Odunjo jẹ aṣòfin àti mínísítà nílẹ̀ yìí, yàtọ̀ sí pé ó jẹ́ òǹkọ̀wé?
- Ìtàn Àrọ̀gìdìgbà jẹ́ kí ń rò pé bàbá mi yan Yemọ̀ja ní àlè - Ọmọ Fagunwa
- Ó pé ọdún mẹ́rìnlélàádọ̀ta tí Akintola kú, ìdí abájọ ìja rẹ̀ pẹ̀lú Awolowo rè é
Bakan naa ni Akinlade salaye awọn ọna to tọ, ti gbajugbaja ileesẹ Stripe fi dokowo igba milọnu Dọla pẹlu ileesẹ rẹ lori ayelujara.
Yoruba ni ẹsin iwaju ni tẹyin n wo sare, ẹyin ọdọ, ẹ sunmọ bi lati kọgbọn lọdọ ọkunrin onimọ nipa okoowo lori ayelujara yii nitori ẹni to ba mọ ọna, lo yẹ ka tẹle.


