Yusuf Buhari and Zahra Bayero wedding :wo àwòrán àwòdamiẹnu níbi ìgbéyàwó ọmọ ààrẹ Buhari

Published

Awodamiẹnu ni aworan awọn to peju pesẹ sibi igbeyawo ọmọ aarẹ Naijiria Yusuf Buhari

Aworan Yusuf Buhari ati Godswill Akpabio
Àkọlé àwòrán, Godswill Akpabio ati ọkọ Iyawo Yusuf
Ọkọ ati iyawo tuntun Yusuf ati Zahra
Àkọlé àwòrán, Yusuf ati iyawo rẹ Zahra
Yusuf n ki baba rẹ Aarẹ Buhari nibi ayẹyẹ igbeyawo rẹ
Àkọlé àwòrán, Yusuf Buhari ni ọmọ ọkunrin kan ṣoṣo ti aarẹ Buhari bi
Aworan igbakeji aarẹ Naijiria
Àkọlé àwòrán, Igbakeji aarẹ Yemi Osinbajo naa ko gbẹyin nibi igbeyawo yi
Gomina Kayode Fayemi ipinlẹ Ekiti ati awọn akẹgbẹ naa peju sibiigbeyawo yi
Àkọlé àwòrán, Awọn to kọwọrin pẹlu aarẹ ninu wọn lawọn Gomina naa wa
Oni Ife naa wa lara awọn to lọ yẹ aarẹ si nibi igbeyawo ọmọ rẹ
Àkọlé àwòrán, Ọjaja Kini Ooni ile Ife naa ṣoju awọn oriade nibi igbeyawo Yusuf ati Zahra
Aarẹ tẹlẹ ri Goodluck Jonathan ati Buhari
Àkọlé àwòrán, Ibaṣepọ aarẹ tẹlẹ Jonathan ati aarẹ oni Muhammadu Buhari jẹ eleyi to dan mọran
Iyawo aarẹ Aisha Buhari ni iya ọkọ iyawo
Àkọlé àwòrán, Awọn iyawo aarẹ orileede to sunmọ Naijira wa yẹ iyawo aarẹ Aisha Buhari si nibi igbeyawo ọmọ rẹ
Aarẹ Buhari ni Kano
Àkọlé àwòrán, Awọn araalu jade la ti wa yẹ aarẹ si nibi igbeyawo ọmọ rẹ