You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Yoruba Adverb: Ẹ̀kọ́ ráńpẹ́ yìí nípa Ọ̀rọ̀ Àpọ́nlé yóò wúlò fún ọ
Published
Itumọ yekeyeke Ọrọ Apọnle ati bi ẹ ṣe le lo o, awọn apẹrẹ ọrọ apnle ti ẹ le fi kun awọn ọrọ iṣe (Verb) ninu gbolohun ni alaye rẹ jade daadaa ninu kilaasi Akomolede ati Aṣa Yoruba toni.
Ọgbẹni Moses Olayiwola to jẹ olukọ wa lati ileewe Smith International Baptrist Academy ni ilu Ogbomoso farabalẹ la aye awọn ọdọ.
Eyi jẹ anfani fun ẹnikẹni to ba fẹran lati maa lo awọn afikun ọrọ ninu gbolohun rẹ fun apọnle ṣiṣe.
Awọn Iroyin ti ẹ le nifẹ si
- Awẹ́ Gbólóhùn ni kókó tí à ń gbéyẹ̀wò lónìí lórí ètò Akomolede- Olùkọ Olajide
- Kí ni "Future tense" lédè Yorùbá?
- Ṣé ìwọ́ mọ Àrànmọ́ Fáwẹ́ẹ̀lì Yorùbá dáadáa?
- Wo ọ̀nà àrà àti ẹ̀fẹ̀ tí Yorùbá fi ń polówó ọ̀jà láyé àtijọ́ àti òde òní
- Fapá jánú, jẹ orí ahun, okété bórù... gbọ́ lẹ́nu olúkọ́ bóyá o gba ìtumọ̀ àwọn Àkànlò èdè yìí
- Wo ìtàn bí ààlọ́ ṣe bẹ̀rẹ̀ àti onírúurú ààlọ́ àpagbè àti àpamọ̀