Yoruba Adverb: Ẹ̀kọ́ ráńpẹ́ yìí nípa Ọ̀rọ̀ Àpọ́nlé yóò wúlò fún ọ

Àkọlé fídíò, Tóò bá fẹ́ràn àti máa pọ́n ọ̀rọ̀ tàbí èèyàn lé, ẹ̀kọ́ ráńpẹ́ yìí yóò wúlò fún ọ
Published

Itumọ yekeyeke Ọrọ Apọnle ati bi ẹ ṣe le lo o, awọn apẹrẹ ọrọ apnle ti ẹ le fi kun awọn ọrọ iṣe (Verb) ninu gbolohun ni alaye rẹ jade daadaa ninu kilaasi Akomolede ati Aṣa Yoruba toni.

Ọgbẹni Moses Olayiwola to jẹ olukọ wa lati ileewe Smith International Baptrist Academy ni ilu Ogbomoso farabalẹ la aye awọn ọdọ.

Eyi jẹ anfani fun ẹnikẹni to ba fẹran lati maa lo awọn afikun ọrọ ninu gbolohun rẹ fun apọnle ṣiṣe.

Awọn Iroyin ti ẹ le nifẹ si