You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Lagos lockdown update: Ayodeji Tinubu ní àìsí àǹfàní ẹ̀kọ́ ayélujára t'íjọba ń pariwo fáwọn ọmọdé agbègbè òun lòun fi di olùkọ́ fún wọn
Published
Lasiko igbele to waye nipasẹ ajakalẹ arun coronavirus, oniruuru eto lo yipada lawujọ ninu eyi ti eto ẹkọ wa.
Gẹgẹ bi ara ọna lati mojuto awọn iyipada yii lo mu ki ijọba ni ipinlẹ Eko o gbe eto ẹkọ ayelujara ati ti ori afẹfẹ jade.
Amọṣa, bi eto naa ṣe loriyin to, ọpọ akẹkọ ni ko lọtọ si nitori aisi anfani ayelujara ati idakureku ina ọba.
Eyi lo mu ki Ọgbẹni Tinubu Ayọdeji, ninu itara rẹ lati rii pe awọn ewe agbegbe rẹ ko padanu nitori airi anfani ayelujara naa lo fi da eto ẹkọ jẹle o sinmi silẹ eleyi ti awọn eeyan ti n kan sara si bayii.
- Èèyàn 663 ló lùgbàdì àrùn Coronavirus ní Naijiria lọ́jọ́ Ìṣẹ́gun nìkan ṣoṣo
- Oyún oṣù méje ló wà nínú Azeezat, kí wọ́n tó f'òkúta fọ́ ọ lórí pa
- Ojú pópó ni mo dàgbà sí àmọ́ n kò mu igbó, sìgá tàbí ọtí líle rí - MC Oluomo
- Lẹ́yìn tó ṣá Monisola aya rẹ̀ ládá, Oniya ní iṣẹ́ èṣù ni
- Ọ̀rọ̀ Sotitobire tí a dá sí, àwọn aṣòfin àtàwọn àjọ kan ló fi lọ̀ wá- DSS
- George Floyd wọ káà ilẹ̀ lọ nílùú Houston l'Amẹrika
- Ìgbìmọ̀ olùwádìí ilé asòfin Eko ní olórí ilé kò jẹbi ẹ̀sùn ajẹbanu