You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ayodeji Amodu Photoshop: Aláráǹbàraà! Ẹ wo àrà tí ''Ayo the Creator'' ń fi sinimá dá
Published
Oriṣiiriṣii ara ni Ayodeji Amodu ati ẹgbọn rẹ n fi awọn gbajugbaja sinima da pẹlu ohun eelo ti ko wọn rara.
Bi awada bi ere ni awọn mejeeji fi bẹrẹ ṣiṣe ẹda sinima, koda wọn ko ka a si nigba naa.
Ṣugbọn kinni ọhun ti wa di nla bayii debi wi pe awọn gbajugbaja oṣere to fẹran iṣẹ wọn n gboṣuba fun wọn.
- ‘ Oluwo kò gbọdọ̀ darí ìrun ní ọdún Iléyá! ’
- ‘Ẹyin ará Ondo, Eko, Ogun, Osun, Ọyo, ẹ gbàdúrà ò!’
- Hajj: Ǹjẹ́ o mọ pàtàkì Ọjọ́ Àràfá fún àwọn mùsùlùmí?
- Ìbànújẹ́ ni ọdún Orò ma ń jẹ́ fún àwọn obìnrin ní ìlú Ikorodu
- 'Ẹ wo iye tí wọ́n ń ta ẹran àgbò lọ́dún yìí '
- Fulani kò leè dúró, táa bá lo ohun ta jogún lọ́dọ̀ àwọn bàbá wa - Sunday Igboho