Ayodeji Amodu Photoshop: Aláráǹbàraà! Ẹ wo àrà tí ''Ayo the Creator'' ń fi sinimá dá

Àkọlé fídíò, Aláráǹbàraà! Ẹ wo àrà tí ''Ayo the Creator'' ń fi sinimá dá
Published

Oriṣiiriṣii ara ni Ayodeji Amodu ati ẹgbọn rẹ n fi awọn gbajugbaja sinima da pẹlu ohun eelo ti ko wọn rara.

Bi awada bi ere ni awọn mejeeji fi bẹrẹ ṣiṣe ẹda sinima, koda wọn ko ka a si nigba naa.

Ṣugbọn kinni ọhun ti wa di nla bayii debi wi pe awọn gbajugbaja oṣere to fẹran iṣẹ wọn n gboṣuba fun wọn.