Nanny: Èèyàn làwa náà, ẹ yé ṣe wá bí ẹranko

Àkọlé fídíò, 'Àwa táa jẹ́ alágbàtọ̀ gan, èèyàn ni wá, ẹ ye ṣe wa bí ẹranko'
Published

Ọna lo jin, ẹru naa kuku ni baba.

Owe yii lo ṣalaye gẹlẹ bí awọn alagbatọ ninu fọnran yii ṣe ṣalaye bi awọn naa ṣe jẹ eeyan ti Ọlọrun da bii ẹlomiiran ṣugbọn ti awọn to gba wọn si iṣẹ maa n saba yi ero pada nipa wọn.

Awọn alagbatọ jẹ ko di mimọ pe bi kii ba ṣe bi awọn ọga to gba awọn ṣe n mu awọn ni, ko sohun to buru ninu ibaṣepọ to dan mọran.

Wọn jẹ ko di mimọ pe "ẹni to fẹ wa ba ẹ tọju ọmọ rẹ kan fẹran lati wa ran lọwọ ni".

Ẹwẹ, Pamela Akinboboye jẹ́ onímọ̀ nipa ìṣesí, o tẹnu bọ'rọ lori ohun ti eeyan le ṣe lati gbadun alagbatọ ọmọ rẹ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: