Genort Rohr: A ò ní já ẹ̀yin alátìlẹ́yìn wa kulẹ̀ lónìí
Published
Wakati perete lo ku ki ifẹsẹwọnsẹ laarin ẹgbẹ agbabọọlu Super Eagles ti Naijiria ati ẹgbẹ agbabọọlu orilẹede Cameroon yoo waye.
Ṣe ni ọpọlọpọ ti n gbiyanju lati Sọ àsọtẹ́lẹ̀ orílẹ̀èdè tí yóò borí ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ t'òní
BBC Yoruba ti mu ọrọ wa latẹnu awọn agbabọọlu gangan funra wọn bẹẹ si ni awọn alatilẹyin ikọ Super Eagles atawọn ọmọ Naijiria to wa lorilẹede Egypt naa ti n sọ ero wọn.
Ni bayii, akọroyin BBc Yoruba mu iroyin wa latọdọ akọnimọọgba Super Eagles, Gernort Rohr.