AFCON 2019: Bí Nàìjíríà ṣe gbá eyí tó lọ, mi ò lè sọ àsọtẹ́lẹ̀ti tònìí
Published
Gẹgẹ bi awọn agbabọọlu Naijiria ṣe ti n gbara di fun ifẹsẹwọnsẹ wọn pẹ̀lú ikọ agbabọọlu ti Cameroon, ọkan awọn ọmọ Naijiria naa ti wa loke.
Ṣe ni ọpọlọpọ ti n gbiyanju lati Sọ àsọtẹ́lẹ̀ orílẹ̀èdè tí yóò borí ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ t'òní
Awọn ololufẹ ikọ super Eagles to n gbe orillẹ̀ede wọn larugẹ ni o yẹ ki awọn agbabọọlu gan ni imọ lara eyi ki wọn si lo gbogbo ọgbọn ati agbara ti wọn ba ni lati mu ori awọn ololufẹ wọn wu.
Bi awọn kan ṣe n sọ idi ti wọn ko fi ro pe Naijiria yoo bori Cameroon bẹẹ ni awọn mii n ṣa n fẹ́ẹ̀ ki Naijiria bori.