AFCON 2019: A bọ̀wọ̀ fún orílẹ̀èdè wa ju àwọn ikọ̀ míì tí à gba fún - Super Eagles

Àkọlé fídíò, Rohr, Mikel, Musa ní àwọn ń padà bọ̀ bí Abija
Published

Adari ikọ́ agbabọọlu Super Eagles, Genort Rohr atawọn ikọ agbabọọlu rẹ sọ ero wọn lori bi wọn ṣe ṣe e ti Madagascar mu wọn kọ oju awn ara Naijiria soorun alẹ.

Wọn si tun fọwọ sọya fun awọn ọmọ Naijiria pe awọn yoo ṣe ohun gbogbo to yẹ fun awọn ifsẹwọnsẹ to n bọ.

Àwọn ìròyìn mìíràn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí: