Ghana: Nurudeen Adam ní a jẹ́ bíi idán ni

Àkọlé fídíò, Wo bí o ṣe lè kọ ẹ̀nu ìfẹ́ sí obìnrin pẹ̀lú ohun èlò orin yìí
Published

Ni abule Pantam Nyame Koro ti orilẹede Ghana ni Ọgbẹni Nurudeen Adam ti n ṣe iṣẹ gbigbẹ ẹda ohun elo orin àmútọ̀hún wá Xylophone.

Dídún ohun èlò orin Xylophone yii ni Nurudeen ti ṣalaye ọpọlọpọ idan ti o le pa.

Nurudeen ṣalaye pe lai tilẹ la ẹnu sọrọ, bi ọkunrin ba lu ohun elo orin yii bakan, obinrin lee gba fun un lọwọ kan.

Nurudeen Adam ti n ṣe ohun elo orin yii fun ogun ọdun o le bayii ṣugbọn ko ri iranwọ latọdọ ijọba.