You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Alagabagebe: Ẹ fi àmì ohùn Yorùbá sí orí rẹ̀
Published
Ẹ nlẹ n bẹun, gbogbo ọmọ Yoruba atata.
Ki aṣa maa parun ni ojuṣe gbogbo wa.
A tun ti bọ sode lori itankalẹ ede Yoruba ati bi awa ọmọ 'kootu oo jiire' ṣe mọ ami ohun ori ọrọ Yoruba si.
O ya, ẹ wo o ki ẹ k'ẹkọ, ki ẹ rẹrin, ki ẹyin naa si gbiyanju u tiyin.
Idahun ni: Alagabagebe to tumó si eni to maa n se kebekebe, ami ohun rẹ ni: re mi do do re do
- Èèmọ̀! Àrá sán pa ènìyàn mẹ́ta
- A tún ti ṣàwárí omi àjèjì míràn ní Ilé-Ifẹ̀ - Ọọ̀ni
- Olórin Makossa, Koffi Olomidé rẹ́wọ̀n he lórí ẹ̀ṣùn ìfipábánilòpọ̀
- Deji àti Charly Boy tako ara wọn lórí fọ́nrán tó jáde
- Iléeṣẹ́ asọ́bodè ṣe agbéga fún òṣìṣẹ́ rẹ̀ tó kọ̀ rìbá
- Yorùbá, ọmọ ọdún mẹ́jọ tà ọmọ òyìnbò yọ nínú ayò Chess l‘Amẹrika
- Obasanjo sí Makinde: yàgò fún òṣèlú sọ ọ́ sápò
- Kínni ó ń fa ilé wíwó?
- Bàbá pokùnso ní àhámọ́ lórí ẹ̀ṣùn pé ó bá ọmọ rẹ̀ lòpọ̀