Alagabagebe: Ẹ fi àmì ohùn Yorùbá sí orí rẹ̀

Àkọlé fídíò, Alagabangebe: Ẹ fi àmì ohùn Yorùbá sí orí rẹ̀
Published

Ẹ nlẹ n bẹun, gbogbo ọmọ Yoruba atata.

Ki aṣa maa parun ni ojuṣe gbogbo wa.

A tun ti bọ sode lori itankalẹ ede Yoruba ati bi awa ọmọ 'kootu oo jiire' ṣe mọ ami ohun ori ọrọ Yoruba si.

O ya, ẹ wo o ki ẹ k'ẹkọ, ki ẹ rẹrin, ki ẹyin naa si gbiyanju u tiyin.

Idahun ni: Alagabagebe to tumó si eni to maa n se kebekebe, ami ohun rẹ ni: re mi do do re do